Top Songs By Masterkraft
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Masterkraft
Performer
CDQ
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Sodiq Abubakar Yusuf
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Masterkraft
Producer
Lyrics
[Intro]
Owo ọti mi o rale
I go chop this life o daadaa
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
Aniyan ọta mi o wọle
Ọmọde ana ti dagba
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
[PreChorus]
Owo ọti mi o rale
I go chop this life o daadaa
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
Aniyan ọta mi o wọle
Ọmọde ana ti dagba
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
[Chorus]
Aye n lọ, o n lọ, Hennessy n lọ, Moet n lọ
Idan n lọ, o n lọ, owo n bẹ lapo mi o
Aye n lọ, o n lọ, Hennessy n lọ, Moet n lọ
Idan n lọ, o n lọ, owo n bẹ lapo mi o
[Verse 1]
Ori ye filẹ, Alakua nobody fit contest
Ko sọmọ naa absorber go less
Surest plug plenty connect
T'ọn ba gbemu dem go collect
Akoi kudi, akoi bar
Aboki kana lafia ko
Money choke like say na kpo
E choke like say na kpo
Filẹ, ny session na men dey there
See barbeach like say na daycare
Ẹ ṣe moro fun awọn ọmọ ti o ja
Emi naa fẹ lakisa bi agba
Rankadede Mustapha Saliu
Turaki Ilori I sight you
No cap ọga na master
Yẹẹ yẹẹ blow money faster
[PreChorus]
Owo ọti mi o rale
I go chop this life o daadaa
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
Aniyan ọta mi o wọle
Ọmọde ana ti dagba
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
[Chorus]
Aye n lọ, o n lọ, Hennessy n lọ, Moet n lọ
Idan n lọ, o n lọ, owo n bẹ lapo mi o
Aye n lọ, o n lọ, Hennessy n lọ, Moet n lọ
Idan n lọ, o n lọ, owo n bẹ lapo mi o
Aye n lọ, o n lọ, Hennessy n lọ, Moet n lọ
Idan n lọ, o n lọ, owo n bẹ lapo mi o
Aye n lọ, o n lọ, Hennessy n lọ, Moet n lọ
Idan n lọ, o n lọ, owo n bẹ lapo mi o
[Outro]
Owo ọti mi o rale
I go chop this life o daadaa
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
Aniyan ọta mi o wọle
Ọmọde ana ti dagba
Alhamdulillahi for today
Mo lowo, mo lẹnu, mo mọyan o
Written by: Sodiq Abubakar Yusuf