Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Olamide
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olamide Adedeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Semzi
Producer
Luke Campolieta
Mixing Engineer
KennyMixx
Mastering Engineer
Mike Seaberg
Mixing Engineer
Alexander Okeke
Executive Producer
Lyrics
[Verse 1]
Fly to Paris for fitting
Go Cali for meeting
Ibiza mo turn up
Maimi mo de'bẹ
Nokia Turaya
Laye mi o le tire
Gba local gba wire
Eeyan Suko I dey fire
Mo local bi Fuji
Like MJ mo boggie
Pa a danu, fun un lọrun
I been killing this game Ọlọrun
Mo gaza, mo gaza
Ẹjọ riro I no get answer
Send money to aza
I dey para gidi gan-an is a maza
[Chorus]
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye?
Owo mi da?
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye
Don't be a fucking bastard
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye?
Awọn temi wọn n gba lavida
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye?
I no fit joke with my last card
[Verse 2]
Banusọ ma beniyan sọ
Ko ku si pressure
O ni railway o ku ni busstop
Mo gbe fun (Gbasgbos)
Mo gbe fun (Gbosgbas)
Nẹnẹnẹ
Ṣọki ṣọmbọlọ
Ṣọmọ lọ
One on one, maa dẹmọ
Ọpọlọ plus ọpọlọ is equal to ọpọlọ
Baby no wan quanta
Wan die on the matter
Because I no be pata
Hustle blow money like a Santa
Party like Poco
Gbe body like Jago
Ọpọlọ Igbo like Zanku
When the gbẹdu drop baby wọn a ku
[Chorus]
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye?
Owo mi da?
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye
Don't be a fucking bastard
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye?
Awọn temi wọn n gba lavida
Ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye, ṣo n ye?
I no fit joke with my last card
Written by: Olamide Adedeji