Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Small Doctor
Small Doctor
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Temitope Adekunle
Temitope Adekunle
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
2T UPONDEEBEATZ
2T UPONDEEBEATZ
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Ile ti mo wọ, o dile owo, ọna ti mo rin, o dọna ọla
Dem fit use you wait for the right person
Iwọ ni ko da tiẹ mọ, ṣe you know yourself
Ṣo dọga ẹ mọ, ṣe you know your boss?
Seun Pizzle ma n jo gan-an
Fine boy to tun ni money
Ọmọ Abija fi mi lẹ o
Iwọ kọ lololufẹ mi
Batifẹ lololufẹ mi
Ọmọ Abija fimilẹ o
[PreChorus]
Mosafẹjọ ti lo court
Adewale o wale mọ
Innocent ti wọ cell
Adejare ti jẹbi
Ogunfe dun ju maalu
Girls like baloon
Who you you, you
Wey you dey you you you me
Agege ni bread ti bẹrẹ o, hain
[Chorus]
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
[Verse 2]
O riwa o sọjunu
Ṣo le foju yẹn ri nnkan re mọ ṣa?
Wọn le ba 1 wọn fẹ ba 2 wa
God don bless hustle wa
Yamayama na money
So many people corny
Recycle your disciple
Nobody loyal
Tori o tan gen' l'ọn ṣe wale yin o
[PreChorus]
Mosafẹjọ ti lo court
Adewale o wale mọ
Innocent ti wọ cell
Adejare ti jẹbi
Ogunfe dun ju maalu
Girls like baloon
Who you you, you
Wey you dey you you you me
Agege ni bread ti bẹrẹ o, hain
[Chorus]
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Ẹ ma wẹyin o (Wẹn wẹn)
Nitori kini? (Wẹn wẹn)
Nitori igbati (Wẹn wẹn)
Ofofo o dara (Wẹn wẹn)
Written by: Temitope Adekunle
instagramSharePathic_arrow_out