Top Songs By Musiliu Haruna Ishola
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Musiliu Haruna Ishola
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Musiliu Haruna Ishola
Composer
Lyrics
Mo ti wa ri b'aye kin to t'ile wa
Mo ti ṣe'ba l'odo àwọn agba o
Ẹyin agba, e je o tuwa ṣe
Eyin agba o, o-ay
Eyin agba t'e ba ri pe a ṣe yín
E ma ro'jo wa s'ibi t'o ṣoro ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan
Ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan (Ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan)
Eyin agba o, o-ay
Eyin agba t'e ba ri pe a ṣe yín
E ma ro'jo wa s'ibi t'o ṣoro ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan
Gatikule, gatikule
Àti t'eba s'inu ṣáko maja, ogberi to ma je ma ni nkan
Egunjobi Ishola o, iyi t'oba Olúwa fún e ko ni pare l'aye
E ṣ'amin kin gbó
Egunjobi Ishola o, iyi t'oba Olúwa fún e ko ni pare l'aye
E ṣ'amin kin gbó
Ọ̀tá kan bínú lásán, wọn o lè r'ana gbẹ gba, Oba t'o ṣ'oni bo wa ṣ'ola
Ao ni di ako bata l'àwùjọ olórin
Written by: Musiliu Haruna Ishola