Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ay Lemi
Ay Lemi
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Olalemi Odunayo Ezekiel
Olalemi Odunayo Ezekiel
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
MylzSpectrum
MylzSpectrum
Producer
NasMkay
NasMkay
Mixing Engineer

Lyrics

Oh happy day
We dey far away
Go hard or go home
Tálọ fẹ lọ'lé?
Oh happy day
We dey far away
Go hard or go home
Tálọ fẹ lọ'lé?
Oh what a feeling
What a feeling
Tálọ fẹ bẹ?
Tálọ fẹ wá?
Wọ'n ta gírí
Oh what a feeling
What a feeling
Ọmọ òlógo
Bó ṣe ń lọ
Kò gba gidi
Say me no get emotions
Tó bá fẹ bẹ, wọ'n máa já ẹ
Tó bá fẹ sá, wọ'n máa bá ẹ (Tó bá fẹ sá)
Say me no get emotions
Tó bá fẹ bẹ, wọ'n máa já ẹ
Tó bá fẹ sá, wọ'n máa bá ẹ (Tó bá fẹ sá)
Shout out to my mother
Ọpọ' muléro, my pillar
Ìnà lójú bí Godzilla
Ìyá Àyọ, Ìyá ní wúrà
Shout out to my mother
Ọpọ muléro, my pillar
Ìnà lójú bí Godzilla
Ìyá Àyọ, Ìyá ní wúrà
Oh happy day
We dey far away
Go hard or go home
Tálọ fẹ lọ'lé?
Oh happy day
We dey far away
Go hard or go home
Tálọ fẹ lọ'lé?
Oh what a feeling
What a feeling
Tálọ fẹ bẹ?
Tálọ fẹ wá?
Wọn ta gírí
Oh what a feeling
What a feeling
Ọmọ òlógo
Bó ṣe ń lọ
Kò gba gidi
Say me no get emotions
Tó bá fẹ bẹ', wọn máa já ẹ
Tó bá fẹ'h sá, wọn máa bá ẹ (Tó bá fẹ'h sá)
Say me no get emotions
Tó bá fẹ bẹ', wọn máa já ẹ
Tó bá fẹ'h sá, wọn máa bá ẹ (Tó bá fẹ'h sá)
I say
Leave flows for Lemi
Eyan Sparkoranking
Eyan Larry Channels
Òṣé! Nurudeen, Zeez
Say we no forget Popo, Jigan, Bidemi
Super Zee, aunty mi ẹ smile
Té bá rí mi
Oh happy day
We dey far away
Go hard or go home
Tálọ fẹ lọ'lé?
Oh happy day
We dey far away
Go hard or go home
Tálọ fẹ lọ'lé?
Oh what a feeling
What a feeling
Tálọ fẹ bẹ?
Tálọ fẹ wá?
Wọn ta gírí
Oh what a feeling
What a feeling
Tálọ fẹ wá? Tálọ fẹ wá?
Written by: Olalemi Odunayo Ezekiel
instagramSharePathic_arrow_out