Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Portable
Portable
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Habeeb Okikiola
Habeeb Okikiola
Composer

Lyrics

[Intro]
Ilu
[Chorus]
Idọbalẹ f'ori-ade
Ẹ ṣa ti ri p'olowo laye mọ
B'ori ri n fọ yin ẹ lo paracetamol
Ẹdo n ro yin ẹ lo oogun jẹdi
To ba de Lafenwa
Owo la n wa
Ọmọ Ẹgba ko ki n gba igbakugba
Gba iyawo Shefiu ko fi sanwo Alao
Ko s'oogun ọfẹ lọdọ babalawo
[Refrain]
Ẹ sọ fun Durodola
Awọn ballers ti b'olowo lọ
[Verse 1]
Wọn ni mo ṣ'oogun owo
Owo l'ọn ma n fi ṣepese owo
Ko s'oogun ọfẹ lọdọ babalawo
Wọn ni mo ṣ'oogun okiki
Ẹyin naa ẹ lo ṣ'oogun oṣi
Oṣi arata ma rayọ
Lo jẹ k'ọn ma sọ rubbish
Gba fun Muri ni gba fun Gbada
Ohun ti mo ba sọ ni kaye ma gba
[Verse 2]
Idọbalẹ f'ori-ade
Ẹ ṣa ti ri p'olowo laye mọ
B'ori ri n fọ yin ẹ lo paracetamol
Ẹdo n ro yin ẹ lo oogun jẹdi
To ba de Lafenwa
Owo la n wa
Ọmọ Ẹgba ko ki n gba igbakugba
Gba iyawo Shefiu ko fi sanwo Alao
Ko s'oogun ọfẹ lọdọ babalawo
[Verse 3]
Gbele pawo
O ji lo gbowo
Nobody is plain, the stain is different
For every level there's a different devil
Stay prepared for a new level
With a different devil
Dem no dey celebrate failure
I'm a winner I'm not a failure
Dem no dey celebrate failure
[Chorus]
Idọbalẹ f'ori-ade
Ẹ ṣa ti ri p'olowo laye mọ
B'ori ri n fọ yin ẹ lo paracetamol
Ẹdo n ro yin ẹ lo oogun jẹdi
To ba de Lafenwa
Owo la n wa
Ọmọ Ẹgba ko ki n gba igbakugba
Gba iyawo Shefiu ko fi sanwo Alao
Ko s'oogun ọfẹ lọdọ babalawo
[Refrain]
Ẹ sọ fun Durodola
Awọn ballers ti b'olowo lọ
[Outro]
O ti lọ bayẹn emi ọmọ Olumọ
Ade ori ọkin ko n ṣe tẹyẹkẹyẹ
T'ọn ba ni k'ọn lọ pọkunrin wa
Emi ọkunrin re bi'le ba da
To ba de Lafenwa
Owo la n wa
Ọmọ Ẹgba ko ki n gba igbakugba
Gba iyawo Shefiu ko fi sanwo Alao
Ko s'oogun ọfẹ lọdọ babalawo
Ẹ sọ fun Durodola
Awọn ballers ti b'olowo lọ (Ilu)
Shocker lo ṣe beat
Written by: Habeeb Okikiola
instagramSharePathic_arrow_out