Music Video

Portable - Am not a Prisoner [Official Video]
Watch Portable - Am not a Prisoner [Official Video] on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Portable
Portable
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Habeeb Okikiola
Habeeb Okikiola
Songwriter

Lyrics

[Intro]
Ọmọ ologo glorious
Ọmọ ologo latest glory o
From Star to Eagle
Ẹ wa wo grace wey no dey disgrace
Ọmọ Olalomi again o, them call me Portable baby o
[PreChorus]
Them carry me go prison mi o gbaṣọ
Them no sew cloth for me
Ẹ jawọ lọrọ mi (I'm not a prisoner)
Them carry me go prison mi o gbaṣọ
Them no sew cloth for me
Ẹ jawọ lọrọ mi o (I'm not a prisoner)
[Chorus]
Sọrọ mi lẹyin ki n pọlọpaa
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
After God na government
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Federal Government liability o
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Too much pressure ma fẹ bẹ ti fẹ
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
[Verse 1]
Ẹyin kọ lẹ fi mi pamọ
Ọlọrun lo fi mi pamọ
K'ọn ma lọ ri mi tan, ni mo ṣe sapamọ
I'm the new born Fela
Oluwa ni ṣọla
E weight abi e no weight?
E weight o (Ṣo n gbọ?)
Emi ti mo wa loke mo tu wa wa okay
Wọn fẹ ran mi lọ ibi ti mi o dagbere
Ọlọrun ma jẹ, ọlọrun ma jẹ, ọlọrun ma jẹ o
Ko ma lọ d'ọla, kẹ ma lọ ma pe brother yin lẹlẹwọn o
[PreChorus]
Them carry me go prison mi o gbaṣọ
Them no sew cloth for me
Ẹ jawọ lọrọ mi (I'm not a prisoner)
Them carry me go prison mi o gbaṣọ
Them no sew cloth for me
Ẹ jawọ lọrọ mi (I'm not a prisoner)
[Chorus]
Sọrọ mi lẹyin ki n pọlọpaa
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
After God na government
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Federal Government liability o
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Too much pressure ma fẹ bẹ ti fẹ o
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Sọrọ mi lẹyin ki n pọlọpaa
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
After God na government
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Federal Government liability o
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Too much pressure ma fẹ bẹ ti fẹ o
Ma fẹjọ ẹ sun ọlọpaa
Written by: Akanbi Taiwo, Habeeb Okikiola
instagramSharePathic_arrow_out