Top Songs By Musiliu Haruna Ishola
Credits
PERFORMING ARTISTS
Musiliu Haruna Ishola
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Musiliu Haruna Ishola
Composer
Lyrics
Iṣẹ́ Oluwa, ko sẹni tó yé
Iṣẹ́ Oluwa jú t'àfá lọ
Iṣẹ́ Oluwa, ko sẹni tó yé
Iṣẹ́ Oluwa jú t'àfá lọ
L'Ọlọrún Ọba fí gbé wagá
L'Ọlọrún Ọba fí gbé wagá o
Lẹ fín bínu, lẹ fín pègán o
Musiliu, Babatunde
President fún àwọn Alakwala
Kari Naija patapata
Bá n pè olorí, b'olorí n jè
Olorin kànkàn o gbọdọ fohùn
Torí pe, olorí jú olorí lọ
Bá n pè olorí, b'olorí n jè
Olorin kànkàn o gbọdọ fohùn
Torí pe, olorí jú olorí lọ
Musiliu Ishola, l'àṣíwajú yín
Nìbì ka kọrin apala, tó f'ọ́gbọ́n yọ o
È lọ meshien onu yín, gbogbo yín o
È lọ gbẹnu dákẹ́
Babatunde Ishola o
Ọmọ egúngún jọbí
B'orin bá dùn, bí o dùn
Èni gbọ̀n wo lomí àwi
Àwa ni baba, è yè má ṣ'àgidí
B'orin bá dùn, bí o dùn
Èni gbọ̀n wo lomí àwi
Àwa ni baba, è yè má ṣ'àgídí
Ká kọrin, ko dá
Ishola l'asiwaju
Orin tó f'ọ́gbọ́n yọ
Ishola l'asiwaju
Orin gídí
Ishola l'àṣíwajú
Musiliu, ọmọ egúngún jọbí
Written by: Musiliu Haruna Ishola