Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Islambo
Islambo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
Songwriter
Banjoko Abiodun
Banjoko Abiodun
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Vibes Ace
Vibes Ace
Producer

Lyrics

[Intro]
Ọṣẹ o ṣiṣẹ lo jẹ k'ọn wa si church
Ọmọ Musulumi ẹ lọ mosque
[Verse 1]
Hold something
Vibes, Dior
Bọbọ alaṣakaṣa yii
Lamba weigh bi ẹṣẹ Bash Ali
Ẹ le gbegẹ si
A bẹ fẹ sọ lede Gẹẹsi
Una no fit push chest
[Verse 2]
Shey na me you dey talk to
To n miri bi ẹni to wọ port hole
O da pe ẹ ti ment (O da pe ẹ ti ment)
I'm in my Element (I'm in my elele)
Ti n ba pẹnkẹlẹ mess
50 mi o gba cent
Ọṣẹ aanu gbe yin wọ church
Kẹ to gbowo ẹ lọ mosque
Eliza holy before
Eliza see sure odd
And Eliza bet!
Abudul na my guy
And he loyal die
Until Abudul see money
Abudul lie
Is okay
Ẹ wo awọn ọmọ ilu oke
[Chorus]
Ita la wa alanta
Pẹlu awọn ọmọto wọṣọ bi Ayra Star
That’s massive baby
Ehn
That’s crazy baby
[Verse 3]
By the way
A ti gba mule si Ozumba mbadwe
Ẹ ma wo Memuna
Dey play
Emi mumu na
Pe pepsi fun mi ni kunnu na
Am not your mutumina
Is okay
Ewa wo ọmọ ilu oke
Wey won dey form wobey
O wa sare ṣi Opay ki n wo
Ha is okay
Ẹ wo awọn ọmọ ilu oke
[Verse 4]
Ọṣẹ o ṣiṣẹ lo jẹ k'ọn wa si church
Ọmọ musulumi ẹ lọ mosque (Elon Musk)
Ete bon (Ete bon) fri bong (Fri bong)
O ṣe firigbọn
Well bo ṣe n gbọn
Stripper ti o ni pole
O ma dopo mu
Opomulero
Ti o le mule wo (O ṣe)
[Verse 5]
Shine my eye ki n ma ri igbo mi
Southy aibo ni
I like them latina Ebony
Ki n yara feed ego mi
ʼCause well o necessary
They go 6 feet down cemetary
Agba legendary aye wa da
Abi you don’t see the energy
[Verse 6]
Aye wa da?
Aye fẹ ni TBS
Wọn fẹ force wa jẹ, a kọ
Na why all this people no like us
They won chop us like Titus
Wọn fẹ so wa they won tight us
Na why me I get touch
O ṣe Zaki
[Verse 7]
Orin mo n kọ
Ẹ dakun ẹ ma cancel mi
Operation council ẹ jọ
Emi kan n wọmọ ti ma ma ba sun ni
Vanessa call me make I come
Mi o ṣe alapata
But mo n padan
My style so smooth
O o maradan
Alaṣakaṣa pe mi lọba idan
Idan to ju idan till dawn
[Chorus]
Alanta
Pẹlu awọn ọmọ to wọṣọ bi Ayra Star
That’s massive baby
That’s crazy baby
A ti gba mule si Ozumba Mbadwe
Is okay, ẹ wo awọn ọmọ ilu oke
[Outro]
Ọṣẹ o ṣiṣẹ lo jẹ k'ọn wa si church
Ọmọ Musulumi ẹ lọ mosque
Is okay, ẹ wo awọn ọmọ ilu oke
Written by: Banjoko Abiodun, Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
instagramSharePathic_arrow_out