Music Video

Nifemi David EYINJU: OFFICIAL MUSIC VIDEO.
Watch Nifemi David EYINJU: OFFICIAL MUSIC VIDEO. on YouTube

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Nifemi David
Nifemi David
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Nifemi David
Nifemi David
Songwriter

Lyrics

[Chorus]
Katọ to dọmọ lo ti mọ mi
O pe mi lẹyinju
Ki n to dọmọ lo ti mọ ohun maa da o
Ogo fun ẹni to da mi
Katọ to dọmọ lo ti mọ mi
O pe mi lẹyinju
Ki n to dọmọ lo ti mọ ohun maa da o
Ogo fun ẹni to da mi
[Verse 1]
Ewe kan ko ni jabọ
Ko sẹyin Olodumare
Ohun ti mo maa da ti mo n da lọwọ
O ti wa ninu eto baba o
Ẹlẹdaa to da mi
O ma ṣe o
[Chorus]
Kẹjẹ to dọmọ lo ti mọ mi
O pe mi lẹyinju
Ki n to dọmọ lo ti mọ ohun maa da o
Ogo fun ẹni to da mi
[Verse 2]
Eto Ọlọrun ni mi
Ẹda aye o le pe mi laṣiṣe
Ninu eto Ọlọrun ni mo wa
Eyi lo fi fẹtọ fun mi
Ẹtọ eyi logo to ṣe mi yatọ
A o kan da mi kan lasan
O laa da mi ni iri oun
And He took it personal
O pe mi ni ogo ọla ire
Ọrọ ibukun rẹpẹtẹ
Eyi ṣa lẹri ifẹ Oluwa si mi pe
[Chorus]
Katọ to dọmọ lo ti mọ mi
O pe mi lẹyinju
Ki n to dọmọ lo ti mọ ohun maa da o
Ogo fun ẹni to da mi
[Verse 3]
Kẹda aye ma sare ohun to wa leto
Mi o ni o duro ṣugbọn ma kanju
Ma dẹ sare asaju laye
Ẹlẹto ni iṣẹda ko ni rẹ ọ jẹ
O waa ninu eto
Ẹtọ a tẹ ọ lọwọ boya o
O ti mọ mi o
Ka to da mi sinu
Ki n to tinu jade lo ti sọ mi di mimọ
A ya mi sọtọ
Aye mi n bu ọla fun ida ti o laṣiṣe
Pẹki nire ṣe lọdọ emi
Ẹyinju baba
[Verse 4]
O n fogo fun
Aye emi naa to da
O n fọla fun
O n fogo fun ẹda ara ọtọ
O n fogo fun
Ida to da mi o laṣiṣe
O n fọla fun
Mo dupẹ fẹlẹtọọ to ka mi mẹtọọ
O n fogo fun
O ṣe aye mi n fogo fun
O n fọla fun
[Chorus]
Kẹjẹ to dọmọ lo ti mọ mi
O pe mi lẹyinju
Ki n to dọmọ lo ti mọ ohun maa da o
Ogo fun ẹni to da mi
Written by: Nifemi David
instagramSharePathic_arrow_out