Credits
PERFORMING ARTISTS
Sola Allyson
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Sola Allyson
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Sola Allyson
Producer
Sola Allyson Obaniyi
Producer
Lyrics
Mo ki o ki o Olorun gbogbo eniyan ti nbe ninu aye
Olorun gbogbo eran ara
Mo ki o ki o Olorun t'o wa l'ori ite o nibiti imole wa
Olorun gbogbo eran ara
Olorun olugbadura gbogbo eniyan ti nbe ninu aye o
Olorun gbogbo eran ara
Aseda a gbobo eniyan olore iseda
Olorun gbogbo eran ara
Olorun olugbadura gbogbo eniyan ti nbe ninu aye o
Olorun gbogbo eran ara
Ninu imole to ni lo nfun wa lo ateni to mo o ateni ti ò mo lo n janfani ise re
Olorun gbogbo eran ara
Olorun ti gbogbo ede ti gbogbo eya npe bo ogo ni f'ooko re
Olorun gbogbo eran ara
Tani maa ki bi o se'wo
Tani maa sin bi o se'wo
Tal'o to ki bi o se'wo
Tal'o to sin bi o se'wo
Iwo l'o da aye ati orun
Ohun to nmi ise re ni
Eyi ti ò mi nb'ola fun o
Iwo ni Olorun gbogbo aye
Iwo ni Olorun ohun gbogbo
Iwo ni Olorun gbogbo aye
Iwo ni Olorun ohun gbogbo
Mo ki o ki o Olorun gbogbo eniyan to wa lori ile yi aye ka
Olorun gbogbo eran ara
Olorun olugbadura gbogbo eniyan ti nbe ninu aye o
Olorun gbogbo eran ara
Awamaridi ti o se salaye loun kan Olorun iseda
Olorun gbogbo eran ara
Olorun ti gbogbo ede ti gbogbo eya npe bo ogo ni f'ooko re
Olorun gbogbo eran ara
Iwo t'o fe wa l'a nsin
Iwo t'o ke wa l'a nbo
K'o o to da wa l'o ti pese sile
Gbogb'ohun t'aa nilo la nri
Eweko n dagba fun jije wa
Tal'o m'orisun ibi ti omi ti n jade
Iwo ni Olorun gbogbo aye
Iwo ni Olorun ohun gbogbo
Iwo ni Olorun gbogbo aye
Iwo ni Olorun ohun gbogbo
Mo ki o ki o Olorun olugbadura gbogbo eniyan ti nbe ninu aye o
Olorun gbogbo eran ara
Olorun olugbadura gbogbo eniyan ti nbe ninu aye o
Olorun gbogbo eran ara
Imole n tan
Okunkun nsu
Anfani nbe
Ninu ofun wa
Ojo nro
Eweko n gba
Itura nbe
Ninu ise re
Imole n tan
Okunkun nsu
Anfani nbe
Ninu ofun wa
Ojo nro
Eweko n gba
Itura nbe o
Ninu ise re
Imole n tan o
Okunkun nsu
Anfani nbe
Ninu ofun wa
Ojo nro
Eweko n gba
Itura nbe
Ninu ise re
Mo ki o ki o Olorun olugbadura gbogbo eniyan ti nbe ninu aye o
Olorun gbogbo eran ara
Written by: Sola Allyson