Top Songs By Broda Shaggi
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Broda Shaggi
Performer
Pasuma
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Samuel A Perry
Songwriter
Pasuma Wonder
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Broda Shaggi
Producer
BlaqueBeats
Producer
Shaggi Band
Producer
Lyrics
Paso Wonder, Broda Shaggi (hello)
It is time to danciya, oya
Are you ready?
Are you ready to dance? (Le-le-le o)
Are you ready to move?
Shaggi, Paso ti gbé 'jo kàn dé
Óyà (are you ready?) (Oya na)
(Are you ready to dance?)
(Are you ready to move?)
(Shaggi, Paso ti gbé 'jo kàn dé)
Are you ready o?
Are you ready to dance?
Are you ready to move?
Shaggi, Paso ti gbé 'jo kàn dé, ah
(Are you ready?)
(Are you ready to dance?)
(Are you ready to move?)
(Shaggi, Paso ti gbé 'jo kàn dé)
Óyá, dance to the rhythm of music
Ijo loka l'eyi o, no go dey tell me say you don tire
9:30, party ṣí ń lọ ní gbórò
Àwọn ọmọ summer body tẹ ba ri wọn, no go fold
Àwọn ọmọ get inside, no dey rock two, five, five show
Ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ṣ'o le jojo loka? (Le-le, le-le, le-le)
Óyá, k'ọwọ s'òkè (le-le, le-le, le-le)
Ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ṣ'o lé jo-jo loka? (Le-le, le-le, le-le)
Óyá, ma ko mọ lẹ (le-le, le-le, le-le)
Ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le), Shaggi o
O tu wa ni, "Ba' Wasiu o
Bàbá Baraka o, Paso o"
Paso pẹlu Shaggi o
Éyí tún yàtọ o
"Ijo loka," o la pé yi o, wesẹ
Wa m'ọwọ kan s'ibadi
Wa m'ọwọ kan s'ẹgbẹ o
Mushin connect o, Paso Wonder, e-ah
Mo ti l'Olúwa (le-le), ọkàn mi balẹ (le-le, le-le)
Mo ti l'Olúwa (le-le), ọkàn mi balẹ (le-le, le-le)
B'awọn kan ba ṣé k'omo wọn a bẹ (kilẹwi?)
B'awọn kan ba ṣé k'omo wọn a tẹ si
Broda Shaggi o featuring Pasuma ní o
Ijo loka, e-ah
Gbọ, b'awọn kan ba ṣé k'omo wọn a tẹ-
B'awọn kan ba ṣé k'omo wọn a tẹ sí
Pasuma Wonder
Ijoba fuji, ah
Oya, ijo loka l'eyi o (Broda Shaggi, Broda Shaggi)
(Ehn) ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ṣ'o le jojo loka? (Le-le, le-le, le-le)
Oya, ka'wọ s'oke (le-le, le-le, le-le)
Torípé ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ah-ah, ijo loka l'eyi o (le-le, le-le, le-le)
Ọmọde, tàgba jojo loka (le-le, le-le, le-le)
Oya, ma ko mọ lẹ (le-le, le-le, le-le)
Ijo local l'eyi o (le-le)
Thank you
Written by: Pasuma Wonder, Samuel A Perry