Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Bolisco
Bolisco
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Ayinla Bolaji
Ayinla Bolaji
Songwriter
God Over
God Over
Songwriter

Lyrics

[Intro]
Hefty baddest producer
[Verse 1]
Awọn ọmọ akukalashika, wọn ti n bọ, kẹ ya gbọ, kẹ ya fọnka
T'ọn ba ti pejọ ninu sanga, wọn a sa para pẹlu wa a gba co-bukker
Bolisco pẹlu God over bi were bi were la fi n jọja
Awa o ki n ba ara wa ja owo nla l'awa ma fi n jọja
[Verse 2]
Ah
Iba fun awọn ọmọ isatententi karuma tuntin anakunti fakuntin illa fakuntin
Ehn awọn ọmọ yẹn l'ọn n pe ni "Ta-ta-ta-ta", eh alanta
Yeh, o pọ
O ti lọ far far, yeh, o ti lọ far far
Amuludun inu mi dun, amuludun inu mi dun
Bo ko lọ far, bo ko lọ far, bo ko lọ far ko tun bo ko lọ far
Bo ko lọ far, bo ko lọ far, bo ko lọ far ko tun bo ko lọ far
Dem don dey vibe, dem don dey go
Dem don dey vibe, dem don dey go
Yeh, pa-pa-pa-pa-pa-pa, ala kuntri fakuntri, a ti fa a ja, emi ati Bolisco ati lọ
[Verse 3]
Wọn ni kẹ bo lion kẹ ma lọ bo nylon
Wọn ni kẹ bo money gun abi ewo ni were gan-an
Wọn ni bọda Obasa, wọn ni kẹ bo universal
Wọn ni kẹ bo universal ki lo de tẹ wa n sa
Tap tap tap, ẹ bo ko lọ far
BJ Bolisco mi, oyege yaga, original ganster, ogbana singer
[Verse 4]
Awọn ọmọ aunty Yoro, ninu Idi-Oro
T'ọn bani ka ma jọja, wọn ni e ni ka ma fa kolo
Gbe wọn rin, ọmọ oro mi gbe wọn rin
Mi o gbọ nnkan kan
Wọn ti geti mi lọ
Ki l'ọn sọ na?
Ti ko ba ti ja si kudi, pe mi pada ọwọ n ro mi
You say wetin? Ṣe you see me ri?
Ṣo mọ mi ri?
Ọgbẹni ma a ba ti ẹ lọ
Ma yọ part mi lọ, 'cause mo le yọ pari ẹ lọ
Tori ara n kan mi ju iya ẹ lọ
[Outro]
Manny monie ara ma n nkan e
Hefty baddest producer
Written by: Ayinla Bolaji, God Over
instagramSharePathic_arrow_out