Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Seyi Vibez
Seyi Vibez
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Seyi Vibez
Seyi Vibez
Composer
Oluwaloseyi Afolabi Balogun
Oluwaloseyi Afolabi Balogun
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Dibs Tunes
Dibs Tunes
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Diẹ diẹ oh
Onilu mi
(Yo Dibs)
Diẹ diẹ oh
Ayy-ayy, ayy
Sibẹ sibẹ oh
Oluwaloseyi
Sibẹ sibẹ oh
Mm-mm
[Verse 2]
Attack, back to sender, attack
Atta', Tawa, ata-iyatu lilah
AZ, gbe mi de be, Isiwat
Wọn de shin gbo gbedu tiwa
Ayy, wọn o ba
Wọn le, wọn o ba
Marhaba, nasakat
It is the ladies party
I no go tire
O mọ pe mi bad
Exam, mo pass
Younger world
Ṣo, o ma n fa loud?
Mm, koda mo ma n gba ounce
[PreChorus]
Mo pe Ọlọhun ngbagba, mo pe Ọlọhun nkọkọ
He go run am, make everything concur
Chokiricho, chokiricho-cho
All on God, everything on God
Nibi, aye pọ, ṣ'o mọ pe aye pọ gan-an
Ọrọ pọ, booty pọ gan-an
No try do me bad, you go fit to kpai
Emi l'ọmọ t'ọn ni "ko le pa'gan-an" (
Story for the gods, k'oma pa'alo
Ayy, ẹ pa'sẹ fun ijalọ
O ṣe wọn bi idan, baby, my love
You be my spec, truly, my love
[Chorus]
I pray, to my Ẹlẹda
Aje, f'ojojumọ wa mi ṣa
O gbe, o gbe, o gbe l'ẹlẹkẹta
Ahn-ahn-ahn, ẹ ṣe aameen ah
I pray, to my Ẹlẹda
Aje, f'ojojumọ wa mi ṣa
O gbe, o gbe, o gbe l'ẹlẹkẹta
Ahn-ahn-ahn, ẹ ṣe aameen ah
[PreChorus]
Mo pe Ọlọhun ngbagba, mo pe Ọlọhun nkọkọ
He go run am, make everything concur
Chokiricho, chokiricho-cho
All on God, everything on God
Nibi, aye pọ, ṣ'o mọ pe aye pọ gan-an
Ọrọ pọ, booty pọ gan-an
No try do me bad, you go fit to kpai
Emi l'ọmọ t'ọn ni "ko le pa'gan-an" (
Story for the gods, k'oma pa'alo
Ayy, ẹ pa'sẹ fun ijalọ
O ṣe wọn bi idan, baby, my love
You be my spec, truly, my love
[Chorus]
I pray, to my Ẹlẹda
Aje, f'ojojumọ wa mi ṣa
O gbe, o gbe, o gbe l'ẹlẹkẹta
Ahn-ahn-ahn, ẹ ṣe aameen ah
I pray, to my Ẹlẹda
Aje, f'ojojumọ wa mi ṣa
O gbe, o gbe, o gbe l'ẹlẹkẹta
Ahn-ahn-ahn, ẹ ṣe aameen ah
Written by: Seyi Vibez
instagramSharePathic_arrow_out