Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Qdot
Qdot
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Fakoya Qudus
Fakoya Qudus
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Drumphase
Drumphase
Producer
DABEAT HANDLE
DABEAT HANDLE
Recording Engineer
Xsmile
Xsmile
Mixing Engineer
DA BEAT
DA BEAT
Producer
DaBeatHandle
DaBeatHandle
Producer

Lyrics

[Intro]
Ọmọ ọmọ Moria
Eheeh ehh eeh
[Chorus]
Ẹyin ọmọ ọlọwọ idan ẹ ja mi b'ọn ma ṣe n pẹja
Ẹbẹ ni mo bẹ ẹ dakun ẹ mu mi rodo
If e better for you e go better for me
Iṣẹ wo lo n lọ ọrẹ mi ja mi o
Ti n ba ti sun ko ji mi ki irẹsi mi ma lọ jinmi tori
American o ni pẹ ji
Milly Hustle ọmọ Salewe ji mi kakukọ to kọ
America o ni pẹ ji
Wọn ni Arizona o lọ mọ Colorado lo n lọ
America o ni pẹ ji
Ma fi update sabẹ aṣọ iṣẹ wo lo tun n lọ
America o ni pẹ ji
[Verse 1]
Ati igba ti grandma ti ku logun ti bẹrẹ
Awọn ọmọ adugbo mi gan-an wọn ja mi lati'lẹ
Ti n ba bi wọn ki lo n dowo wọn ma ni aago ẹlẹpọn ni
Mo lọ garri o kunna wọn ni ko jọ lẹbu
If you no get money brother you no get level
Ki n ma parọ mo fọ fun Ola ninu Ibadan ni Elebu
Awọn ọmọ keekeeke kan fowo oppress mi
Wọn de America ri o ṣugbọn dollar n'ọn na
[Verse 2]
Table no dey turn again
Akẹẹkọ to fẹ gbeegun ẹyin lo ma joko si
Mo n bẹ 2baba sign me for hypertek o
Ki n to fi carry over pa wọn ninu Yabatech o
Tori iṣẹ bo-o-ji-o-ji-mi ni mo maa n ṣe
Ọlọrun da mi lare igba wo lo ma ba mi ṣe?
Iwọ ni mo mọ mi o mọle adahunṣe
Ẹru yii wuwo ju baba wa ba mi gbe
Orukọ ẹbi maa bajẹ ti iṣẹ yẹn ba lọ cast
Pe Qudus pada lọ gbe calabash
Lootọ family house wa o si n Lekki
Baba mi gbinyanju omi lo pọ jọka lọ
A a ni silver spoon a ni ṣibi onike
O pẹ ki n to mọ
O pẹ ki n to mọ pe o ṣibi onike o le din dodo
[Chorus]
Ẹyin ọmọ ọlọwọ idan ẹ ja mi b'ọn ma ṣe n pẹja
Ẹbẹ ni mo bẹ ẹ dakun ẹ mu mi rodo
If e better for you e go better for me
Iṣẹ wo lo n lọ ọrẹ mi ja mi o
Ti n ba ti sun ko ji mi ki irẹsi mi ma lọ jinmi tori
American o ni pẹ ji
Milly Hustle ọmọ Salewe ji mi kakukọ to kọ
America o ni pẹ ji
Wọn ni Arizona o lọ mọ Colorado lo n lọ
America o ni pẹ ji
Ma fi update sabẹ aṣọ iṣẹ wo lo tun n lọ
America o ni pẹ ji
[Verse 3]
Owo wire ti da aṣeju lowo bene'
Alubarika ni ko digba to ba singbẹrẹ
Ma fọmọ onilẹ we ọmọ Yahoo
Ma fọmọ ẹkun we ọmọ maalu
[Verse 4]
Ti n ba ni ẹ gbe mi, ẹ gbe mi trabaye
Tẹ ba fun mi lọṣẹ ẹ dakun ẹ ṣalaye fun mi
Ẹ gbe mi, ẹ gbe mi bi ti Yungi Du
Mo ti ṣetan lati wa gbọṣẹ dudu
I know sometimes life can be funny
I dey hustle I dey grind make e be for me
No one to pay my bills for me
If I later cashout I know who dey for me
A o ni silver spoon a ni ṣibi onike
O pẹ ki n to mọ
Ṣibi onike o le din dodo
[Chorus]
Ẹyin ọmọ ọlọwọ idan ẹ ja mi b'ọn ma ṣe n pẹja
Ẹbẹ ni mo bẹ ẹ dakun ẹ mu mi rodo
If e better for you e go better for me
Iṣẹ wo lo n lọ ọrẹ mi ja mi o
Ti n ba ti sun ko ji mi ki irẹsi mi ma lọ jinmi tori
American o ni pẹ ji
Milly Hustle ọmọ Salewe ji mi kakukọ to kọ
America o ni pẹ ji
[Outro]
Iṣẹ wo lo tun n lọ na?
America o ni pẹ ji
Ẹ ma pada wọna
America o ni pẹ ji
Written by: Fakoya Qudus
instagramSharePathic_arrow_out