Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
MohBad
MohBad
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aloba Promise Oladimeji
Aloba Promise Oladimeji
Songwriter
Oluwole Daramola Ebenezer
Oluwole Daramola Ebenezer
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
SB
SB
Producer
VERB. AJE
VERB. AJE
Mixing Engineer

Lyrics

[Intro]
Imọlẹ
O mọ pe mo bad
Marlian
[PreChorus]
Ọmọ kan bi hundred
Ọmọ kan bi one million
Ọmọ kan bi two million
Ọmọ namọ pa
Ọmọ kan bi hundred
Ọmọ kan bi one million
Ọmọ kan bi two million
Ọmọ namọ pa
[Chorus]
Biliki pẹlu Tawa
Ko sọmọ lara wọn
Deborah ati Sarah
Ko sọmọ lara wọn
Chioma ati Blessing
Ko sọmọ lara wọn
Rukkah ati Debo
Ko sọmọ lara wọn
[Verse 1]
Ọmọ re abi Omo?
Ẹjẹ re abi zobo?
O loun n ṣe bonaza
O fabẹ ṣe promo lọfẹẹ lofo, mo fọ
Ṣo ri Bukky, ko n ṣọmọ
Ṣo ri Yemisi, ko n ṣọmọ
Ṣọmọ re?
Ọmọkọmọ
[PreChorus]
Ọmọ kan bi hundred
Ọmọ kan bi one million
Ọmọ kan bi two million
Ọmọ namọ pa
Ọmọ kan bi hundred
Ọmọ kan bi one million
Ọmọ kan bi two million
Ọmọ namọ pa
[Chorus]
Chidima ati Mercy
Ko sọmọ lara wọn
Aunty Tiwa
Ko sọmọ lara wọn
Toke Makinwa
Ko sọmọ lara wọn
XI lo fẹ
Ko sọmọ lara wọn
Ọmọkọmọ
[Verse 2]
Definition ọmọkọmọ
Oun lọmọ to gbowo lọ
Definition ọmọkọmọ
Oun lọmọ to boko lọ
If you know you are a real ọmọkọmọ
Ọmọkọmọ yeah ọmọ yamayama
Lemme hear you say yeah yeah
[PreChorus]
Ọmọ kan bi hundred
Ọmọ kan bi one million
Ọmọ kan bi two million
Ọmọ namọ pa
Ọmọ kan bi hundred
Ọmọ kan bi one million
Ọmọ kan bi two million
Ọmọ namọ pa
[Chorus]
Chidinma ati Mercy
Ko sọmọ lara wọn
Aunty Tiwa
Ko sọmọ lara wọn
Toke Makinwa
Ko sọmọ lara wọn
XI lo fẹ
Ko sọmọ lara wọn
Ọmọkọmọ
[Outro]
Ko sọmọ lara wọn
Ko sọmọ lara wọn
Ko sọmọ lara wọn
Ko sọmọ lara wọn
Written by: Aloba Promise Oladimeji
instagramSharePathic_arrow_out