Lyrics

Sitting at the corner
(Gbáyì)
Porsh or you local
(Gbáyì)
Smoking marijuana
(Gbáyì)
Me say you sitting at the corner
(Gbáyì)
Porsh or you local
(Gbáyì)
Smoking marijuana
(Gbáyì)
Ìbádì ẹ lọ nínú bumshort
Ìbádì è yò, porobo
Porobo, porobo, porobo
Ìbádì ẹ lọ nínú bumshort
Ìbádì è yò, porobo
Porobo
Porobo, porobo
Oh Lord
CDQ, gbáyì
Wọn pé è
Vado, gbáyì
Ọmọ, we are hotter than them
Hello maami
Aye fe tawafa
Ìbi l'owó wà, gbágbè Sarafa
Baba loju agbalumo ni, ọmọ lé yin ko?
B'oṣe n set è, fìdí èhn, èyan Shonekan
You don't wanna lack what you like, girl
I don't need you to say it
I know what you like, girl
Good sex, raw cash, that's what you like, girl
Real G standing here but you say you like girls
Olomì lo má rè, mi o lé seke
Mo ṣe t'ìbílè ati àwọn ọmọ Ibo
Èyan Nweke
Mogan ni Carifi, fún wọn n leg over
Mumsi anybody is allowed, àfi kógbà
Wọn ṣe àdúrà aini rídí fún àwọn oloso
Àbo ti o ri èni sidi e wo, ko le páwo
Ìgbá la'npá, ènikan o le pá áwo
Ba mi jú ìbadí ṣ'eyin fún CDQ ati Vado
If I get 100k, I go give you 99k
Me I go hold 1k
Mà worry, mí o ni ké
Iyèn nà tó mi jè wanke
Ma listen si àwọn èké
Mo roké, so jú èké, dèyín lèyín bàdí oké
Ìbádì ẹ lọ nínú bumshort
Ìbádì è yò, porobo
Porobo, porobo, porobo
Ìbádì ẹ lọ nínú bumshort
Ìbádì è yò, porobo
Porobo
Porobo, porobo
Forget about the fact that I'm popular
Make me your pencil, you be the sharpener
Á mà n nod anybody ka to sharpen, naa
Scratch plate eh, 360 on a circular
CDQ yeye pelu Vado
Sensa mi tiwa, eminado
Èjẹ k'ọmọdè wá, èwo l'embargo
Gustavo lọmọ l'atilè, èyan Pablo
Making money in a way ti mi o lé ṣ'àláyè
Fly from a plane to another plane bi omo garaje
Owú àbọdí kopè lẹnu òná ofún ni ojẹ
But shọkí lobe oge, ègbá yi nà kẹ bárajè
This is for my ladies on a bum short
Your body is a killer like a gunshot
Summer body re, bi jollof pot
Mami wọn pé è, please let me share your hotspot
Sitting at the corner
(Gbáyì)
Porsh or you local
(Gbáyì)
Smoking marijuana
(Gbáyì)
Me say you sitting at the corner
(Gbáyì)
Porsh or you local
(Gbáyì)
Smoking marijuana
(Gbáyì)
Ìbádì ẹ lọ nínú bumshort
Ìbádì è yò, porobo
Porobo, porobo, porobo
Ìbádì ẹ lọ nínú bumshort
Ìbádì è yò, porobo
Porobo
Ṣe oun lo pọ̀ tó yi?
Porobo, porobo
Ṣe oun lo pọ̀ tó yi?
Ṣe íbádì lo tó yi?
Written by: NS/NS
instagramSharePathic_arrow_out