Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Reminisce
Reminisce
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Remilekun Khalid Safaru
Remilekun Khalid Safaru
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Sarz
Sarz
Producer

Lyrics

[Intro]
Oyi rappers
I've moved on to greater things
I'll see you in a jiffy
Enh, enh, thank you
How far, how far
1827765
Report your location
Sarz on the beat aka Nacademus
O ja (O ja), ilefo aye
Movement
[Verse 1]
Wọn ni mo n big meech (Mo n big meech)
Mo n larry hoover (Mo n larry hoover)
Mo n nawọya (Mo n nawọya)
O n dun bi Woofer (O n dun bi Woofer)
Kalọ l'Oniru (Kalọ l'Oniru)
Kalọ fa skunk (Kalọ fa skunk)
Lọdọ Sikiru (Lọdọ Sikiru)
Ṣe iyẹn lo gẹ punk (Oh oh)
[PreChorus]
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle oh!
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle
L'adugbo mi oh
Leave it (Ẹ ma lọ demo') Calm down, calm down
Let's go there
[Chorus]
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken
Naro bi pako
[Verse 2]
Wọn ni mo n big meech (Big meech)
Mo n Fally Ipupa
(Fally Ipupa) Fuck it, mo n Cabo Snoop (Cabo Snoop)
Emi papi chula (Papi chula)
Ọmọ mo sun ti, abi kerosine (Kerosine)
No slow motion, action to supreme
[PreChorus]
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle oh!
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
Ẹruku wọle (Oh oh)
L'adugbo mi oh
Calm down, calm down (Ẹ ma lọ demo) Ọmọ wa ni ẹ jẹ o ṣe
Let's go there
[Chorus]
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken
Naro bi pako
[Verse 3]
Wọn l'emi local boy (Shit)
Raskimono
How bitch, I am learnin'
But local lo n gbowo
Shit, ilefo Cherubu
F'amure han wọn
How, Reminisce to ja
Sarz, o ya fo jẹ 'ọn gbọ
[Chorus]
Okay
What is this?
Awọn ọmọ n ko mi
O n d'orunkun
(O ya) Emi ralli piper
Ile fun ku (Ilefo)
Let's go there
[Outro]
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken (Ayayaya)
Naro bi pako (Ayayaya)
Kako bi chicken
Naro bi pako
Let's go there
[Outro]
Kalọ mo sa fun ẹ to junction
Obinrin joko, ewe lo fi n run pako
Eruku bi silencer
Eke to ja ti gbẹgbẹ wọle
Eke to ja ti gbẹgbẹ wọle
Sheyman on the mix
Written by: Remilekun Khalid Safaru
instagramSharePathic_arrow_out