Credits
PERFORMING ARTISTS
Aṣa
Vocals
Ayako Tanaka
Violin
Benjamin Constant
String Conductor
Caroline Lasfargues
Violin
Emmanuelle Cohen
Cello
Françoise Gnéri
Viola
Jean-Paul Minali-Bella
Viola
Kaneko Lyodoh
Violin
Laurent Vernerey
Bass Guitar
Michaël Ohayon
Acoustic Guitar
Nadine Pierre
Cello
Pascal Danae
Electric Guitar
Regis Ceccarelli
Drums
Virginie Buscail
Violin
COMPOSITION & LYRICS
Aṣa
Composer
Benjamin Constant
String Arranger
Cobhams Asuquo
String Arranger
PRODUCTION & ENGINEERING
Christophe Dupouy
Strings Engineer
Lyrics
[Verse 1]
Awe ibo lo lọ ka
Ta n fi wa ọ ka
Ibi o ba lọ jẹ a mọ
[Verse 2]
Aunty to n gbe le itosi
O wa ọ wale yii
Ati ọjọ mẹta atabọ
[Verse 3]
O wi pe o
O loyun fun ọ
Oyun oṣu meji
O loyun fun ọ
A ni wi pe o
O loyun fun ọ
Iwọ, iwọ na
O loyun fun ọ
[Chorus]
Wahidi ọmọ Sekina
Ọmọ Muyina
Ọmọ Mohammed
Wahidi ọmọ Sekina
Ọmọ Muyina
Ọmọ Mohammed
[Verse 4]
Aunty to loyun fun ọ
O to bi ọ l'ọmọ
Iwọ, iwọ naa
Aunty to loyun fun ọ
Ani o to bi ọ l'ọmọ
Iwọ, iwọ naa
[Verse 5]
O bimọ oh oh
O bimọ
O bimọ oh oh
Ọmọ sọ layọ
Irẹ lo ni mu, ẹsẹ
Irun ori
Iwọ dudu, ọmọ pupa
Ba wo lo ṣe ri
[Chorus]
Wahidi ọmọ Sekina
Ọmọ Muyina
Ọmọ Mohammed
Wahidi ọmọ Sekina
Ọmọ Muyina
Ọmọ Mohammed
[Verse 6]
Ẹ wa wo ija lafin ọba Ejigbo
Ah, atabo, atakọ
Wọn ja laafin ọba, laafin ọba oh
[Verse 7]
Wahidi ọmọ Muyina ni
Ọmọ Sekina
O foju mi ri mabo
Mabo nile, mabo loko
Mabo l'Ekoo
[Verse 8]
Mama to bi mama rẹ ni mama mi
Emi naa bi temi, bi temi
T'ọmọ lọwọ, f'ọmọ lọyan
Ma ko tirẹ ba mi ba mi
[Verse 9]
Abọ ọrọ la n sọ f'ọmọluabi
Bo ba denu rẹ a dodindin
Dindi
Written by: Aṣa