Featured In
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Aṣa
Vocals
Ayako Tanaka
Violin
Benjamin Constant
String Conductor
Caroline Lasfargues
Violin
Cobhams Asuquo
Background Vocals
Emmanuelle Cohen
Cello
Françoise Gnéri
Viola
Janet Nwose
Background Vocals
Jean-Paul Minalli-Bella
Viola
Kaneko Lyodoh
Violin
Laurent Vernerey
Upright Bass
Magic Malik
Flute
Nadine Pierre
Cello
Pascal Danae
Acoustic Guitar
Virginie Buscail
Violin
COMPOSITION & LYRICS
Aṣa
Composer
Benjamin Constant
String Arranger
Cobhams Asuquo
String Arranger
PRODUCTION & ENGINEERING
Christophe Dupouy
Strings Engineer
Lyrics
[PreChorus]
Ojumọ ti mọ
Ojumọ ti mọ mi
Nilẹ yii o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[PreChorus]
Ojumọ ti mọ
Ojumọ ti mọ mi
Nilẹ yii o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[Chorus]
Ẹyẹ adaba, ẹyẹ adaba
Ẹyẹ adaba ti n fo lokeloke
Wa a ba le mi o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[PreChorus]
Ojumọ ti mọ
Ojumọ ti mọ mi
Nilẹ yii o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[PreChorus]
Ojumọ ti mọ
Ojumọ ti mọ mi
Nilẹ yii o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[Chorus]
O ya, ẹyẹ adaba (Adaba)
(Ẹyẹ Adaba) Ti n fo lokeloke, loke
Wa a ba le mi o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[Chorus]
O ya, ẹyẹ adaba (Ẹyẹ adaba)
(Ẹyẹ adaba) Ti n fo, n fo, o n fo
Wa a ba le mi o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[Bridge]
E wi ki n gbọ sẹ
[Chorus]
Ẹyẹ adaba (Ẹyẹ adaba)
(Ẹyẹ adaba) Ti n fo lokeloke, loke ode ọrun
Wa a ba le mi o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[Bridge]
Oh oh, o ya, o ya
[Chorus]
Ẹyẹ adaba (Ẹyẹ adaba)
(Ẹyẹ adaba) Ti n fo, n fo, o n fo
Wa a ba le mi o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
[Bridge]
Ẹ wi ki n gbọ sẹ
Ah oh oh oh ohh
Mo rire o
Ire, ire, ire
Mo rire o
[Chorus]
Ẹyẹ adaba, ẹyẹ adaba
Ẹyẹ ti n fo lokeloke, loke ode ọrun
Wa a ba le mi o
Ojumọ ti mọ
Mo rire o
Written by: Aṣa