Credits
PERFORMING ARTISTS
Aṣa
Performer
Nicolas Mollard
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Aṣa
Songwriter
Nicolas Mollard
Composer
Lyrics
[Verse 1]
Ma yale mi iwọ ọrẹ atojubọ onile
Ma yale mi iwọ ọrẹ agbọkọ-ọlọkọ
Ma yale mi iwọ ọrẹ adugbo
Ma yale mi, ma yale k'ọmọ
[Verse 2]
Ọrẹ ti mo mu bi aburo
Ọrẹ, ọrẹ ti mo ṣe dara dara
Ọrẹ ti mo finu han
O wa da mi o, o tu mi sita
[Bridge]
O dabi ọrọ ana
Eh ih, ọrọ ano
[Verse 3]
Don't come to my house
Iwọ ọrẹ eke adugbo
Don't come to my house
Iwọ ọrẹ adaleru
Ma yale mi, iwọ ọrẹ kofẹnifẹre
Ma yale mi o, ma yale rara
[Verse 4]
Iṣẹ ni mo lọ wa lọjọ yii o
Ọkọ to fẹ mi sile
Ko ku lọ waṣẹ ṣe
Lawọn mejeeji, wọn bẹrẹ iṣekuṣe
Wọn wuwa ọmọde, wọn ṣe bo ṣe wu wọn
[Bridge]
O dabi ọrọ ana
Eh ih, bi ọrọ ana
Eh ih, dabi ọrọ ano
Ah, bi ọrọ ano
[Verse 5]
Ẹ wa woja lọjọ yẹn
Ẹ wa wo ero to tu 'ta
Ẹ wa wẹjẹ nilẹ
Ah ọrẹ, ọrẹ o, o tu mi sita
[Verse 6]
Ma ya e mi oh oh oh
I don't want to see you no more
Ma ya e mi oh oh oh
O ṣe ma bere mi n'le
Ma ya e mi oh oh oh
I don't want to see you no more
Ọrẹ iṣekuṣe kun ọwọ rẹ o
Emi o ti ẹ le payan
Written by: Aṣa, Benjamin Constant, Nicolas Mollard