Credits
PERFORMING ARTISTS
Aṣa
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Aṣa
Composer
Lyrics
[Intro]
Ọrun silẹkun, I wanna have some talk with you, oh-oh
[Verse 1]
Nitori rẹ mo ṣe lọla
Nitori rẹ mo ṣe n ṣoge
Nitori rẹ mo ṣe ra mọto
Mo wolẹ, mo b'Oluwa mi sọrọ
Nitori rẹ mo ṣe wa laye
Nitori rẹ mo ṣe waṣọ sara
Nitori rẹ mo ji lowurọ
Mo wo aye mi lode ye, ya
[Chorus]
Ah-ah-oh, ah-ah-ah-oh
Ah-oh
Iba f'Eledua
Iba f'Eledua, oh, oh
(Ah-oh)
Yeah, yeah, yeah
Ah-ah-ah-oh
Mo wolẹ ye
Mo b'Oluwa mi sọrọ
[Verse 2]
Nitori rẹ mo ṣe gbọroyin ayọ
Laisowo, laisi nnkan kan
Iya oni, layọ ọla o o
B'Oluwa ti wi, bẹẹ naa lo ri
Oh, oh, oh, o wi pe ki n ma ṣe bẹru
So
[Chorus]
Ah-ah-oh, ah-ah-ah-oh
Ah-oh
Iba f'Eledua
Iba f'Eledua, oh, oh
(Ah-oh)
Yeah, yeah, yeah
Ah-ah-ah-oh
Mo wolẹ ye
Mo b'Oluwa mi sọrọ
[Verse 3]
Ah, ninu ipọnju
Ninu idamu
B'emi ba gbọran
Ma wolẹ, ma b'Oluwa mi sọrọ
B'emi o l'eeyan
B'aye ba foju di mi
B'emi o n'ile
Ma wolẹ ma b'Oluwa mi sọrọ
[Chorus]
Ah-oh
(Ah-ah-ah-oh)
(Ah-oh)
Iba f'Eledua
Iba f'Eledua, oh-oh
(Ah-oh, ah-ah-ah-oh)
Oh, oh, oh, oh, ah-ah-ah
Mo wolẹ ye
Mo b'Oluwa mi sọrọ
[Refrain]
Honey
(Ah-oh, ah-ah-ah-oh)
Ninu ipọnju, ninu idamu
(Ah-oh)
B'emi ba gbọrọ
(Iba f'Eledua)
Ma wolẹ ma b'Oluwa mi sọrọ
(Ah-oh, ah-ah-ah-oh)
M'o ni foju sunku mọ o
Aye lọja and ọrun ni'le
Ẹni a fi ba mi
Written by: Aṣa