Lyrics

Intro: They call me fresh out Jimma sun.. Jimma sun leleyi...
IKA...
Hook: Kini mase
ko yemi
atewo mobala
Gbemi Adaniwaye
Oun maje mowaka majen ri wahala
Korimi je kin moke
Amosa momase yori Mayege
Aye timo wa moma jeyan ni be
Oloun ni koseyan nibe
Hmm hmm hmm
Sebi sapa lomu jakoronle
Rich man pikin go think say na race
Poor man chasing and drowning in pains
Rich man pikin go things say na craze
So I’m down on knees
Heaven rain your mercy on me
Make dem pick race ama lewon ba o
Awalangbe won ma lewa bawo
Cos my mama always calling on me
Heaven rain your mercy on me
Make dem pick race ama lewon ba o
Emimadebe moma tun koja o
Tun koja o
Moma tun koja o
Verse 1: Letter kékeré kan mo fe forwardu sota mi...
Ṣèti jẹun léni abi Bread yín shodun butter ni...
Torí ké tó lè decide láti shote eni tolohun gbafun..
Dreamer lè gbodo je coat Joseph tí color gbafun....
0 1 0 every day rich man go think say na binary...
Every là fín bẹ bàbà Kò saanu fún wa finally..
Dream ọmọ tálákà to lóhùn fe ra refinery....
Grace to mú ọmọ òní moruwa tó den tó má ni Ferrari...
Wọn léni tí ó mọ ibi egbe ti lan sareku ni...
Ní Hussein bolt gan ó shey dúró kí no ẹ tó sáré kú ní...
Billion dollar dream láti inú lè wá tio ni ceiling...
Mo ti debi sun laarin awọn ton jẹun... So i know the feeling....
Chinese lóró mi a jọ létí ẹ tó bá tíì jìyà rí...
Ayé ready àti ja ẹ láyà tó bá ti kiya rí...
Ìwọ ni ko jí má sún... Strike bí pò jí là asuu...
Wọn ò lè mú ọmọ ológo gbé òróró ìgbàlà ni ko fi rári.... (IKA!!)
Hook: So I’m down on knees
Heaven rain your mercy on me
Make dem pick race ama lewon ba o
Awalangbe won ma lewa bawo
Cos my mama always calling on me
Heaven rain your mercy on me
Make dem pick race ama lewon ba o
Emimadebe moma tun koja o
Tun koja o
Moma tun koja o
Verse 2:
Every day ni mon gbàdúrà tí mon fín tuhari..
WA se ijoba ayei Baba ní mo fín Buhari...
Mo fe ká àwọn ota mi rii lọ shey Tuale pé Say Baba..
Owo ni koko àgbàdo mi ada Tin ń bá lè gbé sì Baba....
Sho bad tèmi kò bá Pull up in a Mercedes...
Tí Àwọn egbe mi nko lè kemi No pull up in a residence...
Ẹni lowo lologbon,sebi tálákà lapoda.
Patient dog to débi sun lano tí padà papọda..
Trek latogun ó súre pé elese mi shi má dó yọ...
Ariwo Loma pò ó súre pelede mi shi má doyo...
Ọmọ ton ké shia gboyon...oluwa ni comforter....
Atorise jor wá style tèmi kò frontal...
Bread gberufu láyé mi tún wà fi kan butter...
Bo ti wá mọ ni ile gan Ama tún wà bí kan butter....
Ìwọ là mo koko mi mi o ni wà bí kan portal....
Oluwaloseyi...ọtí shina là wá fi kan portal....
IKA...
Hook: Kini mase
ko yemi
atewo mobala
Gbemi Adaniwaye
Oun maje mowaka majen ri wahala
Korimi je kin moke
Amosa momase yori Mayege
Aye timo wa moma jeyan ni be
Oloun ni koseyan nibe
Hmm hmm hmm
Sebi sapa lomu jakoronle
Rich man pikin go think say na race
Poor man chasing and drowning in pains
Rich man pikin go things say na craze
So I’m down on knees
Heaven rain your mercy on me
Make dem pick race ama lewon ba o
Awalangbe won ma lewa bawo
Cos my mama always calling on me
Heaven rain your mercy on me
Make dem pick race ama lewon ba o
Emimadebe moma tun koja o
Tun koja o
Moma tun koja
Written by: Abdul Kabir Olakunde, Diamond Jimma, Kabex, Kusimo Olawale Abeeb
instagramSharePathic_arrow_out