Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ay Lemi
Ay Lemi
Lead Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Daniel Mafikuyomi
Daniel Mafikuyomi
Songwriter
Olalemi Odunayo Ezekiel
Olalemi Odunayo Ezekiel
Songwriter
Nasmkay
Nasmkay
Arranger
PRODUCTION & ENGINEERING
Dante Beatz
Dante Beatz
Producer

Lyrics

Gbèdù tó dùn lórí vocals
Gbèdù tó dùn lórí vocals
Gbèdù tó dùn lórí vocals
Gbèdù tó dùn lórí vocals
Calculator lọwó loader
Gbèdù tó dùn
Calculator lọwó loader
Ọmọ Uni pẹlú folder
Gbèdù tó dùn àti vocals
Foreign boy no be local
Pè mí Lemí
AY cooker
Calculator lọwó loader
Ọmọ Uni pẹlú folder
Gbèdù tó dùn àti vocals
Foreign boy no be local
Pè mí Lemí
AY cooker
Ọmọde gbọ
Ó ní ó dùn ó dà
"Can I take your order?"
"Breakfast or dinner?"
(Gbèdù tó dùn lórí vocals, gbèdù tó dùn)
Ọmọde gbọ
Ó ní ó dùn ó dà
"Can I take your order?"
"Breakfast or dinner?" (Gbèdù tó dùn lórí vocals)
Gbèdù tó dùn lórí vocals
Gbèdù tó dùn lórí vocals
Gbèdù tó dùn lórí vocals
Calculator lowo loader
Gbèdù tó dùn lórí vocals (Omo Daddy Ayo)
Ó fà ayà
Kó tó gbà wire
Ó ká tìrá
Kó tó tirakà
Ó wẹ òṣè
Kó tó wọ'ṣé
Òṣè 12:30
Kó tó wọ'ṣé
Ó fà ayà
Kó tó gbà wire
Ó ká tìrá
Kó tó tirakà
Ó wẹ òṣè
Kó tó wọ'ṣé
Òṣè 12:30
Kó tó wọ'ṣé
Pushing steady
Getting ready
For the trending
Winter ending
Summer loading
Gbedu dropping
For the baddies
And my niggies
They be vibing
To boy Lemi
Shayo with my guys in a Bentley
We no need savings to go Yankee
All thanks to God and Sparkoranking
Nurudeen, Zeez àti Larry
Oya jíjò, jíjò, jíjò, jíjò
Owó tí ẹ fi ń rálé
Láfín rà gbò
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Oya jíjò, jíjò, jíjò, jíjò
Owó tí ẹ fi ń rálé
Láfín rà gbò
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Láfín mu shayo o
Ọmọde gbọ
Ó ní ó dùn ó dà
"Can I take your order?"
"Breakfast or dinner?"
(Gbèdù tó dùn lórí vocals, gbèdù tó dùn)
Ọmọde gbọ
Ó ní ó dùn ó dà
"Can I take your order?"
"Breakfast or dinner?" (Gbèdù tó dùn lórí vocals)
Gbèdù tó dùn
Zero Panic (Gbèdù tó dùn lórí vocals lórí vocals)
Ay Lemi (Gbèdù tó dùn lórí vocals)
Omo Daddy Ayo (Calculator lowo loader)
Zero Panic (Gbèdù tó dùn lórí vocals lórí vocals)
Ay Lemi (Gbèdù tó dùn lórí vocals)
Ay Lemi (Gbèdù tó dùn lórí vocals)
Written by: Daniel Mafikuyomi, Olalemi Odunayo Ezekiel
instagramSharePathic_arrow_out