Upcoming Concerts for L.A.X

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
L.A.X
L.A.X
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Damilola Afolabi
Damilola Afolabi
Songwriter
Akinyinka Kuham Oladimeji
Akinyinka Kuham Oladimeji
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
L.A.X
L.A.X
Recording Engineer
FJ Beats
FJ Beats
Producer
Noah Airé
Noah Airé
Mixing Engineer
Glody Glo Kasongo
Glody Glo Kasongo
Engineer

Lyrics

[Intro]
Izz LA
[Verse 1]
No-no-
Nobody be like zaza o
Came into the game put some jara o
This Fuji thing na we start am
Every year gbẹdu drop we no tire o
You see long time they want to bring me down
Industry they want to cool me down
Mo kọti ikun si wọn and I dey drop my sound
Oluwa dey involved now I dey around
Awọn temi wọn ko mi jẹ
I no care about the ones wey no ko mi jẹ o
You see me, walking billionaire
Me I dey my lane plenty zeros now
Me no care about no awards
Oluwa give me the reward
My fan base na my award o
Wọn pọ bi omi ko dẹ sirọ nbẹ o
[Chorus]
Ẹjẹ mi mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving o
Aje, mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving
Ẹjẹ mi mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving o
Aje, mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving
[Verse 2]
Nobody know how water take enter coconut
Ọmọ atapatadide ninu pọtọpọtọ
Time no dey, time no dey
Iya lọja l'Oshodi, iyalode
O ku le jẹ ọmọ ẹgbẹ ni l'Agege
Ọmọ ẹru le dọba in no time, time no dey, ahh
Time no dey, time no dey
Illahi ọba eleti gbaroye
Reputation is what people think about you
Character is the exact who the fvck you are
Igba ta pe yin, no respond, ẹ gbe call wa
Ko si ringtone abi ẹ block wa
Ẹ ma wẹyin kẹ ma lọ sunle
Tori hold up o ki n mu okada
Igunugun mi o dẹ n jẹ ọfada
Alẹ ṣi ma riran wo
[Chorus]
Ẹjẹ mi mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving o
Aje, mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving
Ẹjẹ mi mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving o
Aje, mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving
[Outro]
Ẹjẹ mi mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving o
Aje, mo wa pẹlu ẹ
Jẹ k'ọn kowo wa, jẹ ki n show loving
Ẹ ma wẹyin kẹ ma lọ sunle
Tori hold up o ki n mu okada
Igunugun mi o dẹ n jẹ ọfada
Alẹ ṣi ma riran wo
Written by: Akinyinka Kuham Oladimeji, Damilola Afolabi
instagramSharePathic_arrow_out