Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Wizka
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Lawal Azeez Ajibola
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Lyquidmix
Producer
Wavy TK
Mixing Engineer
Lyrics
[Verse 1]
Jerimoya lẹẹmeje
Ọba to n gbedekede
Ọba to dari sanmọ meje
Ọba ti o ma lafiwe
[Verse 2]
Ẹ j'a sọtan janmọ meji
L'ọn ba lọ sọdọ woli
K'ọn le dọla ko le niyi
Woli sọ iran fun akọkọ
Wi pe owo n bọ wa fun un
Ṣugbọn lala a pọju
Fun ọmọ ẹda Adamu
[Verse 3]
Woli tẹsiwaju lọ
Lo ba sọ iran fun ikeji
Wi pe a rowo ojiji
Lo ba ko aje meji
Lọwọ awọn janmọ meji
Wi pe ẹ wi ihun tẹ fẹ si
Lowurọ fun ọjọ meje
Ṣugbọn ranti ẹni keji
[Chorus]
Ọba mi a maa dara ṣa
Rara ko sẹni bi
To ba deni o le dọla
Ko dodi fun ikeji
Ọba mi a maa dara
[Verse 4]
Oju aye
O ba gbọ ihun ti time sọ
Wa mọ pe ko salaye
O ni bi ti ere puzzle mọ
Nikeji atakọkọ
Woli ma lo fedefọ
Wi pe ko sanybody
Tayin nnkan t'Oluwa wi
Akọkọ l'Ọlapọju
O sọrọ s'Ajepọju
Ikeji dẹni ipọnju
O poṣe ju aje sọnu
Ilahi, Ọba yii ma ṣe wo mi
Abiamọ to n lọja yii
Mo dero to nigba yii
Illahi
[Chorus]
Ọba mi a maa dara ṣa
Rara ko sẹni bi
To ba deni o le dọla
Ko dodi fun ikeji
[Chorus]
Ọba mi a maa dara ṣa
Rara ko sẹni bi
To ba deni o le dọla
Ko dodi fun ikeji
[Outro]
Ọba mi a maa dara ṣa
Rara ko sẹni bi
To ba deni o le dọla
Ko dodi fun ikeji
Written by: Lawal Azeez Ajibola