Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Rybeena
Rybeena
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Atanda Oluwaseun Adewale
Atanda Oluwaseun Adewale
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Seanz Beatz
Seanz Beatz
Producer

Lyrics

[Intro]
Ọgba, Agege
Agege, Ọgba, Pencinema, Agege, Ọgba
Ẹ wọle, ẹ jokoo
Ẹ wọle, ẹ sit down
Agege, Ọgba, Ọgba, Ọgba
Ọgba
[Verse 1]
Jawesẹnu bo dija
Ṣo stubborn, ṣo le prodigal?
One kilometre waka you go see dealer
For my own hood straight death if we hold ripper
No think am
Abobi no fit carry last
Even Lanre no fit tẹri mi ba
Iwa ọmọ lo ma n mu ọmọ loruka
She was born poor bawo ni ko ṣe ni gold digger
[PreChorus]
Life goes on but ko sọrọ
Mo mọ pe ọrọ mi o ni su Ọlọhun
Nibi t'awọn kan jẹya lawọn kan dan o
Ba ṣe b'ẹru ṣa la b'ọmọ
Mo ni pe ma la, a ti kọ ọ na o
But ọkan mi mo ma sọ ọ tan o
Wọn ni pe a le d'eeyan ẹyin jẹ Ọlọhun
Awọn ti wọn o ni ti wọn n bẹ Ọlọhun
Ṣe wọn ṣẹ Ọlọhun ni
[Chorus]
Some have food but cannot eat
Mo ba lọ hospital mo fẹ maa ke
Some can eat but have no food
Them no get shishi jọ ba wọn ṣe
Salary wọn oṣu meji o to mi gba 4G kan n'Ikate
Man, I've been steady living
Na by your grace wọn o f'agbara ṣe
[Refrain]
Wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
[Verse 2]
See, we all live to survive every day
Reality wey dey hit na some kind heavyweight
Like afọju wey go blind date
Tell me how he wan recognize fine face
Overthinking dey cause migraine
And e don dey be like iṣẹ aye
Even igbo no dey high me again
O ma ṣe
[PreChorus]
Life goes on but ko sọrọ
Mo mọ pe ọrọ mi o ni su Ọlọhun
Nibi t'awọn kan jẹya lawọn kan dan o
Ba ṣe b'ẹru ṣa la b'ọmọ
Mo ni pe ma la, a ti kọ ọ na o
But ọkan mi mo ma sọ ọ tan o
Wọn ni pe a le d'eeyan ẹyin jẹ Ọlọhun
Awọn ti wọn o ni ti wọn n bẹ Ọlọhun
Ṣe wọn ṣẹ Ọlọhun ni
[Chorus]
Some have food but cannot eat
Mo ba lọ hospital mo fẹ maa ke
Some can eat but have no food
Them no get shishi jọ ba wọn ṣe
Salary wọn oṣu meji o to mi gba 4G kan n'Ikate
Man, I've been steady living
Na by your grace wọn o f'agbara ṣe
[Refrain]
Wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
[Outro]
Jawesẹnu bo dija
Ṣo stubborn, ṣo le prodigal?
Iwa ọmọ lo maa n mu ọmọ loruka
She was born poor bawo ni ko ṣe ni gold digger
Written by: Adewumi Theophilus, Atanda Oluwaseun Adewale
instagramSharePathic_arrow_out