Lyrics
Ọgba, Agege
Agege, Ọja, Pencinema, Agege, Ọja
Ẹ wọle, ẹ jo ko
Ẹ wọle, ẹ sit down
Ọja, Ọja, Ọja
(Seanz Beatz, where you at?)
Jawesẹnu, bo di ja
Ṣo stubborn, ṣo o le prodigal?
One kilometer waka you go see dealer
For my own hood, straight death if we hold ripper
No think am, Abobi no fit carry last
Even Lanre no fit tẹri mi ba
Iwa ọmọ lo ma n mu ọmọ loruka
She was born poor, ba wo ni ko ṣe ni gold digger
Life goes on, but ko sọrọ (sọrọ)
Mo mọ pe ọrọ mi o ni su Ọlọhun (su Ọlọhun)
Nibi t'awọn kan jẹya l'awọn kan dan o (kan dan o)
Ba ṣe b'ẹru ṣa la b'ọmọ (b'ọmọ)
Mo ni pe maa la, a ti kọ ọ na o (kọ ọ na o)
But ọkan mi, mo maa sọ ọ tan o (sọ ọ tan o)
Wọn ni pe a le d'eeyan, ẹyin jẹ Ọlọhun? (Jẹ Ọlọhun)
Awọn ti wọn o ni ti wọn n bẹ Ọlọhun (bẹ Ọlọhun)
Ṣe wọn ṣẹ Ọlọhun? (Ṣẹ Ọlọhun)
Some have food but cannot eat
Mo ba lọ hospital mo fẹ maa ke (ke)
Some can eat but have no food
Them no get ṣiṣi, jọọ, ba wọn ṣe (ṣe)
Salary wọ oṣu meji o, to mi gba 4G kan n'Ikate ('te)
Man, I've been steady living
Na by Your Grace, wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
Ko sọrọ eh
Wọn o f'agbara ṣe
See, we all live to survive every day
Reality wey dey hit, na some kind heavy weight
Like afọju wey go blind date
Tell me how he wan recognize fine face
Na over thinking dey cause migraine
And e don dey be like iṣẹ aye
Even igbo no dey high me again, o maa ṣe
Life goes on, but ko sọrọ (sọrọ)
Mo mọ pe ọrọ mi o ni su Ọlọhun (su Ọlọhun)
Nibi t'awọn kan jẹya l'awọn kan dan o (kan dan o)
Ba ṣe b'ẹru ṣa la b'ọmọ (b'ọmọ)
Mo ni pe maa la, a ti kọ ọ na o (kọ ọ na o)
But ọkan mi, mo maa sọ ọ tan o (sọ ọ tan o)
Wọn ni pe a le d'eeyan, ẹyin jẹ Ọlọhun? (Jẹ Ọlọhun)
Awọn ti wọn o ni ti wọn n bẹ Ọlọhun (bẹ Ọlọhun)
Ṣe wọn ṣẹ Ọlọhun? (Ṣẹ Ọlọhun)
Some have food but cannot eat
Mo ba lọ hospital mo fẹ maa ke (ke)
Some can eat but have no food
Them no get ṣiṣi, jọọ, ba wọn ṣe (ṣe)
Salary wọ oṣu meji o, to mi gba 4G kan n'Ikate ('te)
Man, I've been steady living
Na by Your Grace, wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
Wọn o f'agbara ṣe
Ko sọrọ eh
Wọn o f'agbara ṣe
Jawesẹnu, bo di ja
Ṣo stubborn, ṣo o le prodigal?
Iwa ọmọ lo ma n mu ọmọ loruka
She was born poor, ba wo ni ko ṣe ni gold digger
Writer(s): Atanda Oluwaseun Adewale
Lyrics powered by www.musixmatch.com