Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Dami Drizzy
Dami Drizzy
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Dami Drizzy
Dami Drizzy
Songwriter

Lyrics

[Verse 1]
Take it or leave it
Ẹsin to wu mi ni ma ṣe
Ko dẹ si ẹsin to wu mi o lẹyin iṣẹṣe
Ifa olokun a tun ori ẹni ti o sunwọn ṣe
Iwọ laṣiwaju wa ti ko le jẹ ki awa ṣiṣe
[Chorus]
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Iṣẹṣe a gbe wa o
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Iṣẹṣe a gbe wa o eh
[Verse 2]
I no come to spoil any religion or tradition o
Ṣugbọn laye mi mi o ni ba wọn sọ kọtankọtan o
Ọrọ otitọ o n'Ifa ni ki a maa jisọ o
Atẹ orin ti mo pa Ifa jọwọ wa ba mi ṣọ o
Lokeloke lọla erin
Lokeloke lọla ẹfọn
Awa ti a gba Ifa gbọ wọn maa ba wa yọ
Ẹ ba wa kede lọ pe ẹsin Ifa maa n bọ
Asiko ti waa to ki awa oniṣẹṣe wa pitan
[Chorus]
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Iṣẹṣe a gbe wa o
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Iṣẹṣe a gbe wa o eh
[Verse 3]
Awa ti kọgbọn
Wọn fẹ ki a labọ
Oke agba la wa gun o wọn fẹ ka jabọ
Ṣugbọn Ifa o gba fun wọn
Ani loju wọn
Ni Ifa ma gba aye lọ
Gọngọn a sọ
[Chorus]
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Iṣẹṣe a gbe wa o eh
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Ẹyin ọmọ eriwo
Iṣẹṣe a gbe wa o eh
Written by: Damilola drizzy
instagramSharePathic_arrow_out