Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Dami Drizzy
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Dami Drizzy
Songwriter
Lyrics
[Verse 1]
Ti ifa ba ṣe wa loore ẹ jẹ ka maa dupẹ
B'ẹdu ba ṣoore fun wa ẹ jẹ ka maa ṣọpẹ o
Bi ọlọṣa koni lẹru lọ lo ma jẹ
Ta ba ṣoore funni ti ko ba ti ṣọpẹ o
Ẹ jẹ ka fi taratara ka fi sinfa
Gbogbo ogo lo yẹ ifa o, ẹ jẹ ka ma yin ifa o
[Chorus]
Gbefa ga, gbefa ga, gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko daradara
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga, iye
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
[Verse 2]
Logba rẹ
Logba rẹ daradara
Ifa ẹlẹri-ipin, asọrọ eni dayọ
O ti fẹ sọrọ ẹ dayọ
Jọwọ tẹle
Ifa lọna iye
Oun lọna ara
Ọna a tun aye ẹni ṣe
Ifa lọna iye
Oun lọna ara
O maa ọrọ ẹ dayọ
[Chorus]
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
Gbefa ga mo ni kẹ gbefa ga
To ba tasiko yin o ẹ ṣe ko dara
Written by: Damilola drizzy