Credits

COMPOSITION & LYRICS
Stephen oghenetega Ifedayo
Stephen oghenetega Ifedayo
Songwriter

Lyrics

[Intro]
Ọrẹ jọ figbo 'lẹ
Ọrẹ jọ figbo 'lẹ
Ọrẹ jọ figbo 'lẹ
Ọrẹ jọ figbo 'lẹ
Emi gan-an mo fẹ figbo 'lẹ
Amọ igbo ni o fẹ fi mi silẹ, mo gbe
[Verse 1]
Mama call me everyday wọn ni ki n figbo 'lẹ
My papa call me everyday wọn fẹ ki n figbo 'lẹ
But me I get like ten dealers friends t'ọn maa n fun mi nigbo lọfẹẹ
Cana o, ẹ gba mi o, bawo ni mo ṣe fẹ figbo 'lẹ?
[Verse 2]
Ọmọ, mo fẹ fi banti l'ẹ
Mo fẹ figbo 'lẹ
Mo ti fi colo 'lẹ (Aje)
Mo ti fi banku 'lẹ (Normal)
Igbo ni o fẹ fi mi silẹ (Mo gbe)
Ti n ba tun wapo mi ma tun ba'gbo nbẹ
Lana mo fẹ figbo 'lẹ
Igba ti maa tun wọ yara, mo tun ba'gbo
[Chorus]
Easy-easy-easy is steeze easy-easy brother see me
Ẹrọra maa bẹna sewe, ẹ rọra pass ewe o
Make una no go pass away o
Figbo 'lẹ
Ṣo le figbo 'lẹ ah?
Emi gan-an mo fẹ figbo 'lẹ
Amọ igbo ni o fẹ fi mi silẹ, mo gbe
Ah, figbo 'lẹ
Ọrẹ mi ṣo le figbo 'lẹ?
[Verse 3]
Ani pe ko figbo 'lẹ, ahhh, yeah!
E dey make me reason, e dey give me joy
But e dey burnt my kidney, e dey roast my lungs
Oh my God, oh my God! Save my soul I don't wanna die young
[Chorus]
Easy-easy-easy is steeze easy-easy brother see me
Ẹrọra maa bẹna sewe, ẹ rọra pass ewe o
Make una no go pass away o
Figbo 'lẹ
Ọrẹ mi ṣo le figbo 'lẹ?
Emi mo fẹ figbo 'lẹ
Ti n ba tun wapo mi ma tun ba'gbo nbẹ
Ṣo le figbo 'lẹ?
Ọrẹ mi ṣo maa figbo 'lẹ?
[Outro]
Otega
Kan bayi o
Jogbo street o
Written by: Stephen oghenetega Ifedayo
instagramSharePathic_arrow_out