Credits
PERFORMING ARTISTS
Asake
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Ahmed Olalade
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Magicsticks
Producer
Nicholas Cavalieri
Engineer
Lyrics
(Ọlọlade mí, Aṣakẹ)
Èmí mí kọ, Ọlọrun mà ní
Èmí mí kọ, Ọlọrun mà ní
Àwá kọ ọ-ọ-ọ
Èmí mí kọ o, Ọlọrun ma ní
Tá lo gbọn t'Ọlọrun? (Ọmọ ọgbọn)
Kò sí anybody to lọ gbọn t'Ọlọrun
Tí wọn bá buga ẹ, oya gbà f'Ọlọrun
Àwọn tí wọn buga mi, wọn tí sá pá mọ o
Wọn ti sá pá mọ o
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Àwá kọ ọ, Ọlọrun mà ní o
Oh-oh, oh, èmí kọ o, Ọlọrun mà ní o
Ọmọ, no be me, ṣebí na God
Carry me from down straight to the top
2020, it was real tough
Fall for ground, almost gave up
Mó fún wọn l'Ọmọ Ọpẹ, mó dẹ jẹ lọ
Go naked in my room and speak to God
Baba God, I no sabi all
So, guide me, as I dey move on on-on
Tá lo gbọn t'Ọlọrun?
Kò sí anybody to lọ gbọn t'Ọlọrun
Tí wọn bá buga ẹ, oya gbà f'Ọlọrun
Àwọn tí wọn buga mi, wọn tí sá pá mọ o
Uhn, wọn ti sá pá mọ o
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Àwá kọ ọ, Ọlọrun mà ní o
Oh-oh, oh, èmí mí kọ o, Ọlọrun ma ní o
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Àwá kọ ọ, Ọlọrun mà ní o
Oh-oh, oh, èmí mí kọ o, Ọlọrun mà ní o
Ńkán-kán o gbọdọ ṣe àwọn ọmọ ológò o
Mímí kàn o gbọdọ mí àwọn ọmọ Ọlọrun o
Alhamdulillah, I'm a brand-new man
(Tune in to the king of sounds and blues)
Writer(s): Temitayo Kareem, Ololade Ahmed
Lyrics powered by www.musixmatch.com