Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Asake
Asake
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Olamide Adedeji
Olamide Adedeji
Songwriter
Ahmed Olalade
Ahmed Olalade
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Magicsticks
Magicsticks
Producer
B.Banks
B.Banks
Recording Engineer
Nicholas Cavalieri
Nicholas Cavalieri
Engineer

Lyrics

[Chorus]
Awodi fo loke o fẹ d'Oluwa
Ẹ ri bi, ẹ ri bi, I wonder
Wonder shall never end, like Pasuma I wonder
I wonder, American wonder, whoa
Ki ni reason, ki ni plan, ki ni scope, why the beefing?
Catfish lori titi, jẹ ẹ bi chicken, ṣọbọlọyọke ju billing
Iwaju gan-an easy, ẹyin o ṣe lọ, ọmọ iya mi ṣo ti ri nsi?
My ship never sinking, mo kanaku mo jiggy
They wanna know what I'm thinking
[Verse 1]
Many, many things I no fit ṣalaye
2022 mo ge wọn trabaye, oh
Oluwa lo ge, from the slum to the top
Emi kọ, awọn kọ wọn o le t'Ọlọrun
Iṣu jọba lori iyan kẹnimaani jọba oṣika
Ojo lọkọ agbado as e de go jasi, my ****
Aroma jogẹ, aroma le wọn, aroma de 'bẹ fa 'bẹ ya, oh
Mo ge wọn bi Babayaro, akabikaola o ya ka'bi lori awa, oh
[Chorus]
Awodi fo loke o fẹ d'Oluwa
Ẹ ri bi, ẹ ri bi, I wonder
Wonder shall never end, like Pasuma I wonder
I wonder, American wonder, whoa
Ki ni reason, ki ni plan, ki ni scope, why the beefing?
Catfish lori titi, jẹ ẹ bi chicken, ṣọbọlọyọke ju billing
Iwaju gan-an easy, ẹyin o ṣe lọ, ọmọ iya mi ṣo ti ri nsi?
My ship never sinking, mo kanaku mo jiggy
They wanna know what I'm thinking
[Outro]
They wanna know
They wanna know
Aroma jogẹ, aroma le wọn, aroma de 'bẹ fa 'bẹ ya, oh
Mo ge wọn bi Babayaro, akabikaola o ya ka'bi lori awa, oh
Written by: Olamide Adedeji, Ololade Ahmed
instagramSharePathic_arrow_out