Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Asake
Asake
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Ahmed Olalade Asake
Ahmed Olalade Asake
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Magicsticks
Magicsticks
Producer

Lyrics

[Intro]
Organise
Every other day I organise
Eh, oh
[Chorus]
Organise
Every other day I organise
Some of us are wise
Every other person over wise
O logbọn ju, o gbọn, o gbọn, o gbọn
Iwọ lo gbọn ju
Agbọngbọn ju, ọgbọn, a ma m'ọlọgbọn gọ
O ti lọgbọn ju
[Verse 1]
Based on one or two pọlọpọlọ
Eeyan Kogbagidi, ọpọlọ pọ
Hmm dakun jẹ n sinmi, ṣe emi j'Ọlọhun
Emi yatọ s'awọn kan, ka mi sọtọ, ka mi sọtọ
Ọjọgọ jọgọ, ẹ gba lọgọ lọgọ lọgọ, to ba fuck up
See tonight for the club we go turn up
Everybody ready pop, ibi pọ gan-an, ibi pọ gan-an
[Verse 2]
Gbagbe oṣi (Ey, ey), awa nikan ni ko s'oṣi (Ey, ey)
I no go let anyone control me
Anything wey I wan do, I go do
Gbagbe oṣi (Ey, ey), awa nikan ni ko s'oṣi (Ey, ey)
I no go let anyone control me
Anything wey I wan do, I go do
[Chorus]
Organize
Every other day I organize
Some of us are wise
Every other person over wise
O lọgbọn ju, o gbọn, o gbọn, o gbọn
Iwọ lo gbọn ju (Ọgbọn, Sodiki)
Agbọngbọn ju, ọgbọn, a ma m'ọlọgbọn gọ
O ti lọgbọn ju
Written by: Olasunkanmi Temitayo Kareem, Ololade Ahmed, Stephanas Boman
instagramSharePathic_arrow_out