Top Songs By Tunji Oyelana
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tunji Oyelana
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Tunji Oyelana
Composer
Lyrics
Eni n binu
Koma ma binu
Onibaje ye sebaje
Alaru ton Je buredi
Se awo orie lonje tikomo
Iwo aseni
Ye seni mo
Oni Jamba ye seka mo
Alaru ton Je buredi
Se awo orie lonje ti komo
Aronipin ranti iwaju
Aiye le yipada bo dola
Alaru ton Je buredi
Se awo orie lonje ti komo
Eni fe sare ko ma sare
Ma di eni ton satire lese mu
Alaru ton Je buredi
Se awo orie lonje ti komo
Written by: Tunji Oyelana