Top Songs By Ebenezer Obey
Credits
PERFORMING ARTISTS
Ebenezer Obey
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Ebenezer Obey
Songwriter
Lyrics
Eye to bá farawegun
Eyin aro ní o sun
Awala lulú ma ma Lu tana
Awa náà kọ o Oluwa ọba ma Ni
Awa la pede ma ma pe tesi
Awa náà kọ o Oluwa ọba ma Ni
Alulu yi titi rè ìlú òyìnbó
A bà wọn dé Amerika
Àìmọye igba
Àìmọye igba
L'abawọn dé ilu òyìnbó
L'abawọn dé Amerika
Ohun tí a lè jẹ nile ayé
Ọla Eledumare ni
Ohun tí a jẹ nile ayé se
Ọla Eledumare ni
Ẹjẹ ka s'adura f'ọmọ ẹgbẹ àwa ọ
Kolori ma ku l'ewe
Komo eyin ma ku l'ewe
Omidan ki I kú
Ilẹ i rofo
Adiro I gbóná kale o
Ará wá a le
Adehun kan wà tí mo b'oluwa ṣe
Orí mi na gbagbe adehun wà
Ba ba ṣòwò ká rere ọja je o
Konise owo máa lówó lọwọ
Kaboyun ile ma bi tibi tire
Àgan tí o bí fún wọn lọmọ gbejo
Adehun kan wà tí mo b'oluwa ṣe
Eledumare baba
Orí mi ma gbàgbé adehun wà
Ẹkilọ' fún bọbọ yen
Ko ye gbero búburú síwá
Eni to ba ba wà rí, kò ba wà sọfún wípe abẹrẹ a lọ
K'ọna okun to di
Keregbe to fọ'
Deyin leyin odo
Keregbe to ma fọ' o
Deyin leyin odo
Abínú eni deyin leyin mi
Keregbe to fọ' deyin leyin odo
Written by: Ebenezer Obey