Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
King Sunny Ade
Performer
COMPOSITION & LYRICS
King Sunny Ade
Songwriter
Lyrics
[Intro]
Aba, gbass
[Verse 1]
Ẹ gba yii ẹ tọwo
(Aba, gbass kẹlẹlẹ)
Ẹ ba gba yii ẹ gbeyẹwo
(Aba gbass kẹlẹlẹ)
Awa ti d'eti aṣọ wa mu ni gẹngẹn
Ẹ ba tẹle mi kalọ sagbo Golden Mercury
Nibi t'ọlọmọge ti n f'ọmu lulu f'ọkunrin jo
Aba, gbass kẹlẹlẹ
Written by: King Sunny Ade