Top Songs By JuniorBoy
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
JuniorBoy
Performer
COMPOSITION & LYRICS
JuniorBoy
Composer
9ice
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Chilly Ace
Producer
Lyrics
[Intro]
Its Chilly its Chilly on the mix
Irifa muri ka ma
Ma seriki fami
Irifa muwa da kaliga
Junior boy ma famiusi dai ka, ha ha ha
I be the girl dem sugar (Ancestor)
Ah ah ah (Milẹ milẹ ti)
[Verse 1]
Life na toxical sugar
Aye ti mo wa mi o wa jẹya
Mo ti ṣeribomi pẹlu irapada
Mo dẹ ti fọwọwẹwọ pẹlu agbalagbas
Mo ni Baba ti ṣeleri pe mo maa debẹ
Mo ti lọ mọ yin lọwọ o, enemies ẹ ma lọ bẹ
[Chorus]
Cos mo ti feeyan mimọ ṣọrọ
Ye ye ye ye
Mo ti dawo ile-aye
Mo ti mọyan mọyan
Mo ti d'wo ile-aye
A ni mo ti feeyan mimọ ṣọrọ ṣọrọ
Onpeni ni ṣọla
Mo ti dawo ile-aye
Mo ti mọyan mọyan mọyan (Mọyan mọyan)
Mo ti dawo ile-aye
Onpeni ni ṣọla
Milẹ milẹ, ti ti
Mo ti dawo ile-aye
[Verse 2]
Mr Jẹgẹdẹ Risi naa ti n ko mi jẹ
Awọnu fẹlẹ ko jẹ a ri ikun ẹni fẹ geni jẹ
Tatalọ gbaṣamọ kuro lọdọ mi
Ṣo gbọ? Again
Ṣisẹntẹle
Ẹni o gbede a gbeke
Ẹni o ja a gbọfe
O ya again, DJ bring it back again
Emi ọmọ mọnimọni mo ti mọ Junior Boy
Emi ọmọ mọnimọni mo ti mọ Chilly Ace
Emi ọmọ mọnimọni mo mọ Charles Lawal
Emi ọmọ mọyanmọyan Coded, Coded, Coded
[Chorus]
Mo ti feeyan mimọ ṣọrọ
Ye ye ye ye
Mo ti dawo ile-aye
Mo ti mọyan mọyan
Mo ti d'wo ile-aye
A ni mo ti feeyan mimọ ṣọrọ ṣọrọ
Mo ti dawo ile-aye
Mo ti mọyan mọyan mọyan (Mọyan mọyan)
Mo ti dawo ile-aye
[Verse 3]
Ndi bo kwenu eyin temi kweze nu
Junior boy dey hail o
Oba goal I dey hail o (Mo ti mọyan mọyan)
Laulau Bido I dey hail o (Mo ti mọyan mọyan)
IBD Dende (Tori mo ti mọyan mọyan)
Ojemba Dudu (Mo ti mọyan mọyan)
Q Money, Money o
I dey hail o
Mo mọ Shina Pellar
Ani mo ti mọyan mọyan
Mo mọ Obanla family
Mo ti mọyan mọyan
Toyin Kolade, you you yeah
[Verse 4]
Emi ọmọ mọnimọni mo ti mọ chilly ace
Emi ọmọ mọnimọni mo ti mọ Charles lawal
Emi ọmọ mọnimọni
Mo mọ Aloma
Emi ọmọ mọnimọni
Mo ti mọ Dr Dren
Emi ọmọ mọnimọni
Mo ti mọ Wesco
Emi ọmọ mọyanmọyan
Mo mọ Madfundz
Badboy Anonymous
Ijọba Sinzu
Ebay Carder eeyan Small Doctor
Tunde Moore awo ile-aye ni mi sẹ
Ẹyin temi I hail o (I hail o)
[Outro]
Risi ṣe'wọ lo gbodo mi?
Ṣe'wọ lo gbodo mi?
Ọmọ aye to gbodo mi
O yẹ ko ti mọ Synergy
Coded to gbodo mi o ti mọ Synergy
Junior Boy to gbodo mi o ti mo Synergy
Charles Lawal
Wọn i mọ Synergy
Written by: 9ice, JuniorBoy