Top Songs By Paul Tomisin
Credits
PERFORMING ARTISTS
Paul Oluwatomisin Olowolagba
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Paul Oluwatomisin Olowolagba
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Jerrydepianist
Producer
Lyrics
Ati odo re Lati se wa o Eledumare
Orisa Apebo
Orisa Apesin baba mi Baba mi
Baba mi wura
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi
Ati iye mi jesu
Bi ko ba se ti
Bi ko ba se tire
Aye nba ti K'eru mi si igbo
Bi ko ba se ti
Bi ko ba se tire
Ota o ba so mi di eni ana o
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
ah ah afumi nla'nfani nla a
Lati fon epe na kikan
siti omo araye gbogbo
ki won le mo pe iwo ni aseda mi
Iwo ni alamo ire To mo mi re
To da mi pe
To da mi da
Ti o de fi igba kan kan da mi da ko da mi da isoro mi
Omi to gbagbe orisun re o se tan lati je ni
Mi o je gba gbe re o Baba mi Oko mi Orusunmiiii
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi
Ati iye mi jesu
Eni to mu wa lowo da ni ninu irin ajo yi o
Iwo l'orisun mi Aba ni ja majemu eni iwo ni Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Pari pari Ola Pari pari Ogo Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi
Ati iye mi jesu
Oba aiku Oba aisa Oba aidibaje o Odo re lati sewa o Eledumare
Eleduomoare Eleduomoare Eleduomoare Eleduomoare Eleduomoare
Apanla to so ile aye ro
Jesu
Jesu Orisa Apebo Orisa Apesin Jesu Baba mi Baba mi wura
Jesu oh
Jesu
Jesu
Jesu
Jesu oh
Jesu
Jesu
Jesu
Jesu oh
Jesu
Iwo l'orisun mi Jesu Jesu
Ati iye mi jesu Jesu oh
Iwo l'orisun mi Jesu
Ati iye mi Jesu Jesu Jesu Jesu Jesu o
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Iwo l'orisun mi Ati iye mi jesu
Written by: Paul Oluwatomisin Olowolagba