Lyrics

Kata kata duro
Ni keji ara keji
Ni 1930
Aruwoso loke oyeo
Majemu CAC
Ogbagbara otun
Olorun emi mimo
Wa romi lagbara
Kata kata duro
Ni keji ara keji
Ni 1930
Aruwoso loke oyeo
Majemu CAC
Ogbagbara otun
Olorun emimimo
Wa romi lagbara
Olorun Ayodele Babalola
Olorun 1930
Ipe ori kata kata
Olorun imo meta
Ikan ro, ikan gbe
Ikan tutumini mini mini
Nle ooo, Olorun oke Ido
Olorun oke Erio
Olorun Ikeji ara keji
Olorun agbaye o
Olorun ori oke Efon
Olorun awon baba n la baba wa
Aye agbara lawa yio
Waro milagbara
Olorun Babalola
Olorun to rin lori omi ti o de farakomi
Olorun awon baba n la baba wa
Olorun Akande lede
Waro milagbara o
Gba agbara re wo mi
Aye agbara lawa yi o
Agbara towo aye o le ka
Jesu Christ gba
Agbara re wo mi kata kata
Kata kata duro
Nkeji ara keji
Ni 1930
Ariwo so loke oye o
Majemu CAC
Ogbagbara otun
Olorun emimimo wa romi lagbara
Written by: Folasade Akinsunmade
instagramSharePathic_arrow_out