Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Performer
Oladipupo Oladimeji
Oladipupo Oladimeji
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oladipupo Oladimeji
Oladipupo Oladimeji
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Drekiss
Drekiss
Producer
Blaqmix
Blaqmix
Mixing Engineer

Lyrics

[Verse 1]
Olabode lorukọ mi, oriki mi l'Adisa
Wọn mọ mi nilẹ alawọ dudu ni dede Africa
Ambition mi tobi gan-an, ambition mi rọbọtọ
Ki n ma ba awọn eyinbo jẹun, ninu abọ wọn yọkọtọ
B'ọn ba seyinbo si mi, emi naa a dẹ sọ Yoruba
Ki n wa jọba le wọn lori dẹni t'ọn ma sọ dọga
Bi eeyan kan ba bẹ si mi k'ọn lo ba mi ju u sinu tubu
Ẹni tọba ba yaso pa, iru eeyan bẹẹ ko ki n sunmu
[Verse 2]
Illiterate ni mi lootọ iwe ti mo ka o pọ
Ṣugbọn mo mọ maths, mo mọ addition, mo mọ aropọ
Ẹ le romi loju mi tori emi o n ba wọn rarokan
Ti baami o ba lowo maalu ma ya ba wọn paguntan
Emi yatọ si awọn kan, t'ọn ma n fake perfection
Wọn ba ma jin si koto, ka l'ọn take direction
E sẹni yi o mọ tan, e sẹni mistake o le ba
Nnkan tọmọwe ba gba, illiterate o le gba a
[Chorus]
Mo ti ṣetan ẹ gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Ẹ ma fina gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Ah, adonilaya o jẹbi
Aya yin ni ẹ kilọ fun, aya yin ni ẹ kilọ fun, aya yin ni ẹ kilọ fun
Ọrun n yabọ o ki n ṣọrọ ẹnikan, ọmọ yin ni ẹ kilọ fun
Angel Gabriel ẹ fun, angel Gabriel ẹ fun
Mo ti ṣetan ẹ gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Ẹ ma fina gbe mi
O ya ẹ gbe mi
[Verse 3]
Emi lọtọlorin number 1, e dẹ si counterfeit
Iṣẹ eleyii yatọ, iṣẹ eleyii l'ọn n pe ni masterpiece
Bi n ba fẹ tọ loru emi nikan ni mo ma n da piss
So ma lo photobomb selfie mi, ah ti n ba ṣa pics
Shout-out sawọn temi l'Ẹgbaa mo mọ pori yin ma swell
Atawọn t'ọn ma gborin mi t'ọn ma bẹrẹ si ni ma twerk
Awọn ọmọ mi Kafila, awọn ọmọ mi Baliki
Awọn ọmọ to jẹ pe gbogbo abẹ wọn ni mo ṣami si
[Verse 4]
Gbẹgẹdẹ gbina, regede fẹ yẹ ẹ wo (Yẹ ẹ wo)
Ẹ jẹ n fi si yin lẹgbẹ wo
Wọn jọ pe wa si show lọjọ si ṣugbọn ẹ lana emi ni sisi yin dẹ fẹ wo (Fẹ wo)
Ẹ wa dẹni t'ọn kẹsẹẹ bo (Ṣẹ bo)
Ti o ba sẹba lọ jẹ semo
Ko ṣa ti gba kadara lo ṣe koko
Ma pada sẹsẹ aarọ, ma pada si zero
[Verse 5]
Wọn ni pe mo high bi ẹni pe mo ti fa canabis
Emi tun ni rapper to n kọ lyrics pẹlu Arabic
Game changer l'ọn pe mi
Leader of the new school
Awọn agba gan-an ti mọ reason tawọn o dẹ fi ni sun, ahh
[Chorus]
Mo ti ṣetan ẹ gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Ẹ ma fina gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Ah, adonilaya o jẹbi
Aya yin ni ẹ kilọ fun, aya yin ni ẹ kilọ fun, aya yin ni ẹ kilọ fun
Ọrun n yabọ o ki n ṣọrọ ẹnikan, ọmọ yin ni ẹ kilọ fun
Angel Gabriel ẹ fun, angel Gabriel ẹ fun
Mo ti ṣetan ẹ gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Ẹ ma fina gbe mi
O ya ẹ gbe mi
Written by: Oladipupo Oladimeji
instagramSharePathic_arrow_out