Lyrics

(Boss) Jummy Jummy, Jummy, w'oju mi (w'oju mi o) Ikebe sọkutu wọ, wọ, wọ O ṣe mi bi gan, gan, gan Ko si iru ẹ ri, Ọlọrun gbọ Ifẹ rẹ da mi lọrun gan-an Mo fẹ fi ẹ ṣ'aya mi lọrọ-kan Ojojumọ lo n yọ bi o ọjọ Iwọ mo fẹ mari, o l'ẹnikan O pa mi, o pa mi, o ye, mo fọ Whether you be Igbo or Hausa, Yoruba, e no matter Can I know your name, ọlọmọge? Ma ṣe gapa I go pay you my cash Ṣe na lion? Mo ma pa Ẹ gba mi, ẹ ra mi o, mo ti n foju comoti wrapper Awuyewuye o, awuyewuye Awuyewuye o, awuyewuye Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ Awuyewuye o, awuyewuye (awuyewuye) Awuyewuye o, awuyewuye Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ W'oju mi, wo'nu mi Sọ fun mi, ma j'oju mi Ko ni su mi, ẹyinju mi, fara mọ mi Ko s'ẹni to le fun mi, ifẹ rẹ dun bi oloyin Bi mo ri ẹ, o ti yo mi Jọọ, ma ṣe kan'ra mọ mi Whether you be Igbo or Hausa, Yoruba, e no matter Can I know your name, ọlọmọge? Ma ṣe gapa I go pay you my cash Ṣe na lion? Mo ma pa Ẹ gba mi, ẹ ra mi o, mo ti n foju comoti wrapper Awuyewuye o, awuyewuye (awuyewuye) Awuyewuye o, awuyewuye Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ Awuyewuye o, awuyewuye (awuyewuye) Awuyewuye o, awuyewuye Mo r'ọlọmọge to n gbe mi ga, ga, ga (ọmọge) Tẹ n ba wa mi kiri, mo ti gba'le ẹ lọ Ah, ah-ah-ah, ah, mo de W'oju mi, ẹyinju mi Ọmọ Abẹokuta re wa o O ma gba dandan-an ni E si un o ma ṣe
Writer(s): Kusimo Abeeb, Daramola Oluwole Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out