Featured In
Credits
PERFORMING ARTISTS
Reminisce
Performer
BhadBoi OML
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Remilekun Safaru
Songwriter
Akinyinka Kuham Olademeji
Songwriter
Saheed Abeeb Samuel
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Busy
Producer
Lyrics
[Verse 1]
Who Jah don bless, no man can curse
God damn it, no man can touch
I dey okay you know say na squad
Who Jah don bless no man can touch
[Chorus]
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi, ire ni temi
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi
Ire ni Allah biya bukata, ire ni temi
What I have is what I’m giving
What I have dem say is not given
Pari owe tẹ ba bi mi, I show more love that I can receive
What I have is what I’m giving
Wahala ni please don’t give me
Otherside is why I'm singing, o kanlẹ, o kanrun, ọpa tinrin
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi, ire ni temi
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi
Ire ni Allah biya bukata, ire ni temi
[Verse 2]
Ọmọ akin o n fọ f'ọla
Ọdun mejila as customer
Lat'Amoo de Mokola
Winter mejila and 12 summers
Awọn mother**cker n ṣe baller
Gbogbo igba temi n ṣe bomber
Ṣebi ile n'ọn bọla
Mi o le farawe, ọmọ mo ja
Ko gbẹ ri, ko gbẹ ri, apo ṣaṣamura, mo ti fogo wẹri
Ya Allahu, ma jẹ n riyọnu
Gbe mi jina sawọn onisọnu
Ogo to ta sansan bi tafinrin
Ọlọhun ma so mi d'ẹni aijiri
Ṣebi iwọ lo pe mi de'bẹ
Dakun jọ ma fi mi silẹ
[Verse 3]
What I have is what I’m giving
What I have dem say is not given
Pari owe tẹ ba bi mi, I show more love that I can receive
What I have is what I’m giving
Wahala ni please don’t give me
Otherside is why I'm singing, o kanlẹ, o kanrun, ọpa tinrin
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi, ire ni temi
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi
Ire ni Allah biya bukata, ire ni temi
[Outro]
Mi o dẹ ni fọ f'ọla
Ire ni temi
Ire ni Allah biya bukata, ire ni temi
Written by: Akinyinka Kuham Olademeji, Remilekun Safaru, Saheed Abeeb Samuel