Top Songs By Banky W.
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Banky W.
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olubankole Wellington
Songwriter
Sunday Nweke
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Masterkraft
Producer
Lyrics
Masterkraft on the beat
Omoge, jasi, mi o ni Maserati
Mi o le gbe e sinu Bugatti
Ahn, mo ni ko jasi
But mo le kapa e
Ma kapa e
Ti m ba gba e
Ma kapa e
Ma tun toju e
Ma toju e
Ti m ba gba e
Ki lo n se e na, je n fun e nkan
Ki lo fe, ki lo need
Ha, samba
Ki lo n se e na, je n fun e nkan
Ki lo fe, ki lo need
Ha, samba
So fe faaji, king of the Lagos party
Ehn, mi so fe faaji, king of the Lagos party
Omoge, jasi, mi o ni Maserati
Ki lo kan mi kan Bugatti
Ehn, who is your daddy?
Ani mo le kapa e
Ma kapa e
Ti m ba gba e
Ma kapa e
Mo ma tun toju e
Ma toju e
Ti m ba gba e
Ki lo n se e na, je n fun e nkan
Ki lo fe, ki lo need
Ha, samba
Ki lo n se e na, je n fun e nkan
Ki lo fe, ki lo need
Ha, samba
Strong ting, to gbona doko
Stop fronting
Wa gba ko yo
Baby, wa gba ko yo, gba ko yo
Ki lo n se na, je n fun e nkan
O fe tele mister W, what's wrong with you?
Ehn, ehn? Ehn, ehn?
Oya, tele mister W, what's wrong with you?
Ki lo fe, ki lo need
Ha, samba
Ki lo n se e na, je n fun e nkan
Ki lo fe, ki lo need
Ha, samba
Kilo, kilo, kilo n se, je, je n fun e nkan
Ha, samba
Je, je n fun e nkan
Ehn, ehn? Ehn, ehn?
Samba
Samba
Written by: Olubankole Wellington, Sunday Nweke