Lyrics
Pasuma Wonder oh
Ìjọba Fuji oh
Bàbá Wasila
Daddy Rokiba
Qdot lórúkọ mí
(2T upon deebeatz)
Kòye wọn
Wọn fẹ mọ'di abájọ mí
Wọn fẹ mọ'lé Bàbá Alájọ mí
Ọtá fẹ mọ ìgi lẹyìn ogba mí
Wọn fẹ mọ'ye to wa ní ipamọ mí oh
Bàbá mí lókè ń pá mí mọ
Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mọ bẹ oh (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà)
Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)
Ẹ jẹ kà dúpẹ' pé ènìyàn kò l'Ọ-l'Ọlọrun wá
Kà lènìyàn ní, ènìyàn lé ní k'òjò má rọ, sùgbọn
Àdúrà lógbà, àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọn
Kí má wọ jersey, kí má wọ bootu
Penalty mí ó lé jẹ'rín
Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mọ bẹ oh (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà)
Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)
Èmi lẹni t'ayé tí ro (t'ayé tí ròpìn oh)
Pé kólé dá ńkán ire ṣé o ('re ṣé o)
Ṣùgbọn, mó rí àánú ẹ gbà, Olú Ọ̀run o, lo ba mi ṣé oh (Alabi oh)
Wọn sáré, sáré, sáré
Olúwa jú wọn lọ
Wọn gb'ero pé kó bàjẹ́ ní, orí mí ó gbàbọdé o (Paso)
Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mọ bẹ oh (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
Ìṣẹdà mí gbéjà mí jà (gbéjà)
Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)
Bàbá mí tí ṣé, Bàbá mí tí ṣé, Bàbá tí ṣé
Oùn t'aye rope kò ṣé-ṣé, Abaniṣe tí bámí ṣé
Òun tí mo wá lọ Sokoto, o ń bẹ l'apo ṣòkòtò mí
Ọmọ t'ọn ní kó lé pa'gan, ó ko'lé alarinrin
Àdúrà lógbà (àdúrà lógbà)
Àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọn
Kí má wọ jersey, kí má wọ bootu
Penalty mí ó lé jẹ'rín
Wọn fẹ mọ'di abájọ mí (mọ'di abájọ mí)
Wọn fẹ mọ'lé Bàbá Alájọ mí (bàbá alájọ mí)
Ọtá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí
Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh
Bàbá mí lókè ńpá mí mọ
Wọn rò pé ó tàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mọ bẹ oh (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ń pá mí mọ)
(2T on the mix)