Lyrics

(Yo-) (Big Vibez) If to say na me be you If I see Naira Marley Ma ya sare ṣe twale I go ask baba for way Because igi imu jina s'ori Ọmọ ma ra ko to rin Sanmọ o le wa lẹ Ẹjẹ kan mọ pe sanmọ o le wa lẹ Oju ra wọn lọ O skingba kan ju kan lọ A nọ gbe fun kan ju kan lọ Mo lo n bẹ bi kan ju kan lọ And it's all on God (and it's all on God) That we are still on top Anything they like make them talk Oun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ (bhrrr!) O ti ṣẹlẹ bayi Oti di agbo awọn wèrè bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (hello) O ti ṣẹlẹ bayi Oti di agbo awọn wèrè bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (hello) To ba funmi dollar, ma gba (ma gba) To ba funmi naira, ma gba (ma gba) Pounds ma gba (ma gba) To ba funmi l'owo, ma gba (ma gba) Giddem, giddem, gidden, giddem Giddem, giddem, gidden, giddem Giddem, giddem, gidden, giddem Giddеm, giddem, gidden, giddem (bhrrr!) Ayеbo, ayeba Somebody call the popo Baba ibeji, iba jojo T'emi ba n kọ'rin, ki iwọ ma jo (bhrrr!) Ayebo, ayeba Somebody call the popo Baba ibeji, iba jojo T'emi ba n kọ'rin, ki iwọ ma jo O le tẹ 'go mọlẹ, ma lọ t'agba mọlẹ Igo ma n ya 'yan l'ẹsẹ Agba ma surprise ẹ Basically, agba ma n ya 'yan l'ẹnu And it's all on God (and it's all on God) That we are still on top Anything they like make them talk Oun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ (bhrrr!) O ti ṣẹlẹ bayi Oti di agbo awọn wèrè bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (hello) O ti ṣẹlẹ bayi Oti di agbo awọn wèrè bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi To ba fun mi dollar, ma gba (ma gba) To ba funmi naira, ma gba (ma gba) Pounds ma gba (ma gba) To ba funmi l'owo, ma gba (ma gba) Giddem, giddem, gidden, giddem Giddem, giddem, gidden, giddem Giddem, giddem, gidden, giddem Giddem, giddem, gidden, giddem (bhrrr!) (Big Vibez)
Writer(s): Azeez Adeshina Fashola, Chisom Faith Ezeh Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out