Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Bidemi Olaoba
Bidemi Olaoba
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Bidemi Olaoba
Bidemi Olaoba
Songwriter

Lyrics

[Intro]
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Chorus]
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
O ṣe Ọlọrun
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Verse 1]
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mo n fo mo n fo
Revelation la wa fi n fo
Aaye waa da
Aaye to ku aaye blessing
Wa a gba Jesu
Wa a gba favor wa gba glory, wa a gba
Wọn ni ẹ sare, wa a gba
Wa wa wa, sare wa gba Jesu, wa gba
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Chorus]
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Verse 2]
Emi ẹni aye le le le t'aye o ri mu
Imọlẹ t'aye pa pa pa ti o dẹ le ku o
Emi ẹni a ba ta ka fi ratupa
Baba sọ mi di transformer fun awọn ti o nina n'le
Emi ẹni aye le le le t'aye o ri mu
Imọlẹ t'aye pa pa pa ti o dẹ le ku o
Emi ẹni a ba ta ka fi ratupa
Baba sọ mi di transformer fun awọn ti o nina nile
[Chorus]
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Verse 3]
Baye ti fẹ fun mi kọ lo ri o
Ilẹkun tọta ti Baba ti ṣi
Baye ti fẹ fun mi kọ lo ri o
Ilẹkun tọta ti Baba ti ṣi
O gbogo fun ọlẹ iru awa naa
Ilẹkun tọta ti Baba ti ṣi
Arogunjo, Arogunyọ, Arogundade l'Ọlọrun
O n gbe mi fo, o n gbe mi ga
[Verse 4]
O ya sare sọ pe
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mo n fo mo n fo
Revelation la wa fi n fo
Aaye wa da?
Aaye to ku aaye blessing
Ka jẹ chicken, ka jẹ turkey, ka jẹ burger, wa gba
Wa wa wa, sare wa gba Jesu, wa gba
Wa wa wa, o ya ẹ sare wa, wa gba
Wa wa wa, sare wa gba Jesu, wa gba
Emi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Chorus]
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
[Outro]
Thank you Jesus
Thank you Jesus
Thank you Jesus
Aanu rẹ lo n gbe mi fo
Mi o ba ti jabọ ọpẹlọpẹ rẹ
Koto tọta gbẹ fun mi emi kọ ni mo ko si
O gbe mi soke ju awọn ọta mi lọ
Written by: Bidemi Olaoba
instagramSharePathic_arrow_out