Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ajulo Jesu
Ajulo Jesu
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adetunji Ajulo
Adetunji Ajulo
Songwriter

Lyrics

[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare kare o
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
[Verse 1]
Wa gbọ, emi dupẹ oore pe apa aye o ka mi
Emi dupẹ oore pe o da mi si
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi o
Mo dẹ gboṣuba fun ọ, kare o
Emi dupẹ oore pe apa aye o ka mi
Emi dupẹ oore pe o da mi si
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare o
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba (Mo wa yin ọ o)
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare (Ọba ti n ṣoore o)
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba (Mo wa yin ọ o baba mi o)
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
[Verse 2]
Ye, oniduro gbogbo wa
Alanu ẹda, oloore mi to n gbọ jijẹ mimu
Iwọ laṣoore funni ma ṣeregun o
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Oniduro gbogbo wa
Alanu ẹda, oloore mi to n gbọ jijẹ mimu
Iwọ laṣoore funni ma ṣeregun o
Mo gboṣuba fun ọ, kare o
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba (Mo wa yin ọ o baba mi)
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare o
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo dẹ gboṣuba fun ọ, kare kare o
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
[Chorus]
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Ọba ti n ṣoore funni lai wobẹ
Mo wa yin ọ o Baba
Iwọ lo n ṣoore fẹni ti o mọyi
Mo gboṣuba fun ọ, kare
Written by: Adetunji Ajulo
instagramSharePathic_arrow_out