Top Songs By Sula
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Sula
Performer
Barry Jhay
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Barry Jhay
Songwriter
Sula
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Olawale Michael Adibe (Dibs)
Producer
Lyrics
(Vxtis)
Oh-oh-oh
Emi ni Barry, Barry t'ọn ko jẹ
Ṣebi, iwọ to ṣ'ana o
Bo mu eni ṣe ni
Mo ṣe n gbẹsẹ l'ẹkọọkan
To mi s'ọna ire
To ba wa d'ọla ma le pada dupẹ, oh-eh
Yeah, iwọ to ni mi, to l'ẹmi mi
Iro yii to lebọ mi
When enemy say them go put fire for my ṣòkòtò
You fight for me o
You fight
Oh-oh, You fight for me
Odoju t'ọta
O p'ọta lẹnu mọ, ẹ ṣeun
Oh, ta ni ma pe ti wahala bá dé?
Ìwọ naa ni
Ìwọ naa ni, oh-oh-oh
Since I was born, and now I am getting old
I have never seen my Lord change
Oh, no-no
Iwọ lo ṣ'ana o
Bo mu eni ṣe ni
Bi mo ṣe n gbẹsẹ l'ẹkọọkan
To mi s'ọnà ire
To ba wa d'ọla ma le pada dupẹ, oh-eh
Yeah, iwọ to ni mi, to l'ẹmi mi
Ìwọ nikan lo le gba mi la lọjọ-kọjọ
Iwọ nikan lo le tun temi ṣe o
Ko ma s'ẹni naa to le gba'po rẹ laye mi oh
Akaka'tan niṣẹ rẹ o eh, e-yeah, e-yeah
Ta ni ma pe ti wahala ba dé?
Ìwọ naa ni
Iwọ naa ni, oh-oh-oh
Since I was born and now I am getting old
I have never seen my Lord change
Oh, no-no
Iwọ lo ṣ'ana o
Bo mu eni ṣe ni
Bi mo ṣe n gbẹsẹ l'ẹkọọkan
To mi s'ọnà ire
To ba wa d'ọla ma le pada dupẹ, oh-eh
Yeah, iwọ to ni mi, to l'ẹmi mi (yeah)
Written by: Barry Jhay, Sula