Featured In
Top Songs By Naira Marley
Credits
PERFORMING ARTISTS
Rexxie
Programming
Naira Marley
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Chisom Ezeh
Composer
Azeez Fashola
Lyrics
PRODUCTION & ENGINEERING
Rexxie
Producer
Lyrics
O t'ẹsẹ 'le bọ
Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)
Ole l'everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo (Yo, Rexxie 'pon this one)
(Barawo, barawo, barawo)
(Mọ ba ṣa ni barawo)
O tẹsẹ'le bọ (o tẹsẹ'le bọ)
Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)
Ole l'everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
O fẹ ṣe'ka fun mi (o fẹ ṣe'ka fun mi)
Mi o l'ogun, mo ni Kurani (mo ni Kurani)
Mo dẹ n ṣ'adura mi (mo ṣe n ṣ'adura mi)
Allah n gba'dura mi (Allah n gba'dura mi)
A ti lọ, a ti de (a ti lọ, a ti de)
Ẹni ori yọ o di'le (Ẹni ori yọ o di'le)
Ẹni ba lọ l'o ba de, I=igba ti n pada de
Nṣe l'ọn de mi l'ade (nṣe l'ọn de mi l'ade)
K'ade ko pẹ l'ori (k'ade ko pẹ l'ori)
Ki bata ko pe l'ẹsẹ (ki bata ko pe l'ẹsẹ)
K'awọn ọta mi kan l'ẹsẹ
Inside life (inside-)
O ti ri 5 Alive (o ti ri 5 Alive)
Inside life (inside-)
O ti ri Deeper Life (o ti ri Deeper Life)
Inside life, awọn kan n jẹ'ya, awọn kan n chop life
(Inside life) inside life, awọn kan n ṣ'epe, awọn kan n jẹ'wa
Jo soapy (soapy)
Kirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)
Jo soapy (soapy)
Ikoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)
Jo soapy, ninu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)
Jo soapy, to o ba ni iyawo n'le, ko jo soapy (soapy)
Soapy (soapy)
Bọda yi n jo soapy (bọda yi n jo soapy)
Soapy (soapy)
Ab'ẹyin naa soapy? (Ab'ẹyin naa soapy?)
Soapy (soapy)
Single father n jo soapy (single father n jo soapy)
Soapy, ma lọ lo Omo to ba lọ n soapy (soapy!)
Ṣo d'owo mọ? (Ṣo d'owo mọ?)
O wa sọ po o mọ Naira (o wa sọ po o mọ Naira)
O wuwo l'ọwọ
Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira (iwọ ṣaa ṣẹ si Naira)
Aja fẹ de'na d'ẹkun
Kekere ẹkun o ma n s'ẹgbẹ aja (ko n ṣ'ẹgbẹ aja)
Wọn n bẹ ni, ma fọ
Awọn naa o fẹ wahala (awọn naa o fẹ wahala)
I just wanna make mama proud (I just wanna make mama proud)
They want to make mama cry (they want to make mama cry)
Mama you gonna cry no more
Tẹ ba sun'kun gan-an, ẹ o sọ'kun ayọ (ẹ o sọ'kun ayọ)
Tẹ n ba n jo, kẹ ba n yọ (kẹ ba n yọ)
K'ọrọ mi ja s'ayọ (k'ọrọ mi ja s'ayọ)
Inside life, Inside life
Do a one course, it's my life (Ku ro nbẹ!)
Inside life (inside-)
O ti ri 5 Alive (o ti ri 5 Alive)
Inside life (inside-)
O ti ri Deeper Life (o ti ri Deeper Life)
Inside life, awọn kan n jẹ'ya, awọn kan n chop life
(Inside life) inside life, awọn kan n ṣ'epe, awọn kan n jẹ'wa
Jo soapy (soapy)
Kirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)
Jo soapy (soapy)
Ikoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)
Jo soapy, ninu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)
Jo soapy, to o ba ni iyawo n'le, ko jo soapy (soapy)
Soapy (soapy)
Bọda yi n jo soapy (bọda yi n jo soapy)
Soapy (soapy)
Ab'ẹyin naa soapy? (Ab'ẹyin naa soapy?)
Soapy (soapy)
Single, sigle father n jo soapy (single father n jo soapy)
Soapy, ma lọ lo Omo to ba lọ n soapy (soapy!) (Spyrit Mix)
Writer(s): Azeez Fashola, Chisom Ezeh
Lyrics powered by www.musixmatch.com